Afurasí omo ògbó-n-tarìgì egbé òkùnkùn, Baddo, ni owó tè ní Ikorodu ní ìpínlè Èkó Lánàá tí osù kefà di ogbòn (June 30th) gégé bí àwon olùgbé àdúgbò se so, a rí Arákùnrin yí tí ó ń rìn káàkiri agbègbè Obafemi ...
Read More »Ìjoba ìpínlè Èkó dá àwon òsìsé KAI dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won.
Ìjoba ìpínlè Èkó, lábé àse Gómìnà, láti jé kí ìlosíwájú bá ètò ìlera ti dá àwon òsìsé KAI (kick against indiscipline) dúró tí won sì fi LAGESC r’ópò won. Ìgbésè náà, gégé bí ìjoba ìpínlè náà, jé òkan lára ìsàkóso ...
Read More »Àyàngbàjù! Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Evans pe ògá olóòpá l’éjó,
**Àti Àwon Méta Míràn Látàrí Àtìmólé Rè Ní Gbogbo Ìgbà. Ògbó-n-tarìgì gbómogbómo, Chukwudumeme Onuwuamadike tí ìnagije rè ńjé Evans, ó ti pe ògá olóòpá l’éjó, tí orúko rè ńjé Ibrahim Idris àti àwon méta míràn ní ilé ejó gíga ti ...
Read More »Oko mi fi mí sílè nítorí pé mi ò tí bímo. Okàn mi ń pòrúrú… Egbàmí!.
…Mi ò ti è mo bí mo se fé bèrè. Ó dàbí kí ń parí gbogbo rè. Oko mi sèsè fi mí sílè torí mi ò tíì bímo àti wípé kò fé kí won gba àtò rè àti eyin mi ...
Read More »Àwòrán ilé-ìwòsàn Giginju àti irinsé orísirísi ti ilè Kano tí ó jé bílíònù lónà méji àti egbèrin néírà (₦2.8 billion)
Gómìnà ìjoba ìpínlè Kano ti ra irinsé ńlá fún ilé-ìwòsàn Giginju rè tí ó sèsè kó tán ní ìpínlè Ìjoba náà. Àwon irinsé náà ni 1.5Telsa Magnet Resonance Imaging, MRI machine, tí ó rà ní owó tí ó tó mílíònù ...
Read More »Arákùnrin kan se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Èkó.
Arákùnrin kan ní orílè èdè Nàìjíríà tí a mò sí Jefferson Uwoghiren, se ayeye ojó-ìbí omo rè obìnrin pèlú òni (crocodile) ní ìpínlè Edo. Arákùnrin náà tí kò so ohun tí ó fé fi eranko afayàfà náà se, ni ...
Read More »Èsì ìdánwò wo ló dára jù tí o ti gbà gégé bi akékòó ifáfitì tí kò tì parí ?
Gégé bí akékòó tí kò ti parí ní ilé-ìwé gíga ifáfitì, àsìkò kan wà tí a ó rò wípé ayé ti ń se wá, àsìkò kan sì wà tí a ó rò wípé a ga ju ayé lo. Ohun tí ...
Read More »Gómìnà Yahaya Bello ri èro amúnáwà (Transformer) gégé bí isé rè àkókò ní ìpínlè Kogi.
Gégé bí ìròyìn se so, Gómìnà ìpínlè Kogi: Yahaya Bello ri èro amúnáwà tí agbára rè tó Egbèédógún (300KVA) ní òpópónà kan ní Lokoja gégé bí isé rè àkókó léyìn tí ó ti lo odún kan àti ààbò lórí ipò. ...
Read More »Owó te olùsó àgùntàn(pastor) èké kan nígbà tí ó ń gbìyànjú láti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé.
Olùsó àgùntàn èké kan tí a mò sí Osinachi Christopher láti ìpínlè Abia ni won fi s’èsín léyìn ìgbà tí owó ti tèé nígbà tí ó ń gbìyànjú à ti ri ohun tí a kò mò sí ilé onílé ní ...
Read More »Ilé ejó gíga jù dá asòfin ìpínlè Taraba dúró, tí orúko rè ńjé Sani Danladi
Won pàse fun kí ó dá owó osù àti àláwánsì tí ó gbà. Ilé ejó gíga jù ti pàse fún asòfin tí ó ń sojú ilé asòfin àgbà àríwá ti ìpínlè Taraba sani Abubakar Danladi láti fi ipò náà sílè ...
Read More »