Home / Author Archives: ayangalu (page 54)

Author Archives: ayangalu

Gbogbo Ile e ma binu simi ooo

Oro buruku pelerin erin’kkkkkk Mo sese ri eran ewure ni ibi to pokunso so ni in Eran ti moni ki a fe se odun lo pokunso yi ooo Mi o mon nkan to nba leru o erin’kkkkkk

Read More »

IYA wa Bukky Ajayi sun re oooooo

Bi oro aye se ri ni yen oooo Bi poopo sin-sin odun se wa nta. Olodumare ti se bi o se nse fun awon ebi iya wa Bukky Ajayi Iya ti lo ni aro yi o. Gbogbo eyin Omo Ooduarere o ...

Read More »

Tani Onife Si Julo Ninu Awon Osere Meji Yi ?

Read More »

Orunmila o jiire loni oooooo!

Oluwo Agbaye; Olori Awo Ode Isalaye; Ifa a mo oni mo ola bi Oba Olodumare; Igba eran ni a fi i bo’Fa; Aboruboye! Aboyeboru! Aboyebosise! cc- Yeyelufe IyaOgbe OmoEdu Oyewole

Read More »

Idile Alayo – Odun ikerin ree ti mo ti se igbeyawo sugbon…

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. ...

Read More »

Ewu Gereye – Adeyanju Ahmed Akewi Imoran

Iya nii je ta ni moo ri, Owo tabua nii je mo ba o tan Igba taa ba n wo sokoto penpe Baye ba ko ni lona Won le moju fira bi eni ofo se Boo rokele atata bu Aye ...

Read More »

Iwure Osu Tuntun 01.07.2016

E MAA WI TELE MI : ………… *Osu yii, osu aseyori mi ni. *Osu iserere mi ni lase Edumare. *Osu igbega mi ni. *Osu idunnu mi ni. *Owo a fi ilee mi se ibugbe. *Akoba, adaba ko ni je temi. ...

Read More »

Ogulutu Oro Toni – 30.06.2016

Hummmmmm mase afarawe tori ohunti Taiye se tomuje ,kehinde lese koyi lowo.. Beere lowo orire kotolo Pate nibi Oja gbe nta Tori ohun gbogbo lowo ori ni ooo ooo….ire oooo King Ogulutu Oro

Read More »

Ibeere Toni

Nje oda ki Ololufe Meji jo so bi won se gbe igbe aiye won kiwon to pade arawon paapa julo obinrin????

Read More »

Ifa kan lo soro ninu odu mimo re Oni.

Omi pakiti o be ona lori,Ona na pakiti o be omi lori,ipade omi oun ona parapo won je merin adifafun oyigiyigi tin sota omi,awa doyigiyigi ao ku mon oyigiyigi ota omi…….. Ao ni ku ni rewerewe taye n yeni o,oju ...

Read More »