Home / Author Archives: ayangalu (page 55)

Author Archives: ayangalu

Eewo orisa iyawo-aare orile-ede fe nan owo si alafin

Aaa eewo orisa iyawo-aare fe nan owo si alafin sugbon alafin ko(refuse) o kare baami iku babayeye gbogbo eni toba bami ri aisha buari iyawo aare orile-ede wa e bami sofun pe awa ki duro ki oba a ki bere ...

Read More »

Itunmo Ala wipe Olopa mu yin.

Bio Bala alawipe loju orun olopa mue waa bo ninu ewu tio koju dae sungbon ti olopa ba mue tio fi handcuff sie lowo Oranla Kan nbo wa fune AFOWOFA arare ni yio si da oran naa sie Lorun kio ...

Read More »

Itunmo: Bi e ba Lala wipe loju e’n sa ewa

Bi e ba lala wipe loju orun e’n sa ewa loju orun tabi e won ewa loju orun oore ibukun lopo lopo lati odo olorun oba ni ona owo lanla yio si Kano kio yara tete mura si adua ki olorun ...

Read More »

Itunmo Ala wipe e ri obo loju orun

Bi o bala ala wipe loju orun wipe e ri awon obo (monkey) meji loju orun tiwon tele ara won alayi dara pupo olorun oba yio seo loore male gbagbe orore yio dayo ona owo yio la fune beesini bio ...

Read More »

Foto: Baba ati omo

O wu Olodumare lo da erin ni ola, Olodumare loni ko ri be.

Read More »

Omo Olojo Ibi toni

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Olori Aina Orosun ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ninu ...

Read More »

Se Etuntigbo ?

Pekini  ? ohunareoooooooo  

Read More »

Kilode ti iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo?

ojulu ni otito, ao gbo iru eleyi ri a fi d’eru ba oloro ni sugbon eleyi ko mi ni omi-inu kilo se alfa abdul-lateef titilope ifa-iwa(itakure) ki lo de ti iku da emi okunrin-osere yi ni egbodo? aaaaaaa olohun-oba aseyi ...

Read More »

Arewa Toni – Oònirìsà, Àrólé Oòduà!

Read More »

Ifa naa ki bayi wipe

| |   | | |   | | |  | | | |   | YORUBA VERSION: Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isimi oni, emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa OKANRAN IRORUN ...

Read More »