Ikin ifa agbaye/world ifa sacred palm but…we dem boys getting it ready for the festival… Yay??? See more photos after the page break
Read More »E fu’n Foto yii ni Oruko
E daku’n e be wa fu’n foto yii ni Oruko ka’n to dara!
Read More »A ku ojumo oooooooo!
Oba to silekun ojo oni, yoo sina ayo fun wa, yoo sina aje fun wa, A ko no seru egbe wa, ire ayo wa ko ni fo wa ru(Ase). #AKARA_IMORAN : Ma se gbo oro okere, gbiyanju lati wadi ohun ...
Read More »Gbiyanju lati toju obi i re !
Ojumo to mo wa lonii, ojumo ibukun, ojumo igbega, ojumo aseyori, ojumo ire, ojumo itunu, ojumo ayo, ojumo idunnu ni yoo je fun gbogbo wa lase Edumare(Ase). # AKARA IMORAN : Gbiyanju lati toju obi i re, niwon igba ti obi ...
Read More »Llegando a oke igeti home de Orunmila.
Foto kerediti –
Read More »Obara Oturupon/Obara Tiele Corpus by Ifa Chief Priest
Good morning my people, how was your night? Hope it was enjoyed. I wish you all happy new month, may this month bring us everlasting joy and happiness amen. It is OBARA OTURUPON/ OBARA TIELE corpus that revealed this morning, ...
Read More »Idajo mi ree…
Leyin gbogbo atotonu awon agbejoro mejeji ati iwadi to peye, ariipe ojebi esun ti a fikan e, nitori na idajo mi ree, ile ejo yi so e sinu: i) igbega; ii) aseyori; iii) idunnu; iv) ayo; v) ire owo; vi) ...
Read More »Idile Alayo Toni
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Idile Alayo ti ose yi. ...
Read More »Ogulutu Oro Toni
Hummmmmm mase beru #eniyan ju #Eledumare lo… woo orewa Kosi nkan tenikan o fi enikan Se,gbiyanjuy latile koju ota re loni,jeki o mo wipe Akinkanju eyan nio #nje O mo wipe toba ti nberu eyan ju yio pada sorare di Olodumare niwaju ...
Read More »Eeto Owe L’esin Oro 4
Mo ki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro. Laakoko, mo dupe lowo Olodumare ti o funwa ni oore-ofe lati tun pade loni, leyin igba ti a dagbere fun eeto ni ose to koja. Moki kabiyesi ...
Read More »