Home / Àṣà Oòduà (page 159)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Iwure Eyonu Awon Agba

Edumare,Oba Ajiki,Ajige,Oba toto bi aro. Awa dupe lowo re ,pe o yo nu si wa lati atete ko se titi di oni oloni. Jowo Baba Alanu ,masai ko Anu re kuro Lori wa (mi). Jowo Baba ologo lola ,je ki ...

Read More »

Tani oma yin logo ti oba ji?

1.Eledumare 2.Mohamedi 3.Jesu 4. Satani Sojunu ti oba ji

Read More »

E dakun eba wa fun Ogbeni yi ni oruko kan

Read More »

Oruko wo leyin npe oko yi ladugbo tiyin ?

laba tia agbegi ma gbeyawo

Read More »

Kini Won Npe Iru oko yi ni ede Tire ?

Read More »

E bami Dasi Oro yi Eyin elegbe mi…

  Ninu Obi Eni tabi A’ya Eni, ewo lose pataki ?

Read More »

Aje olokun yo fiso sile gbogbo wa ooo

AJÉ Iwọ́nrín Olókun a bi ara á ‘le koko bí ọta, Òhun l’ó d’ifa fún orí Àpéré ọ̀nà ọmọ a t’Àkàrà ṣ’ọlà.. (Ajé brings prosperity. I wish all Ifa University members a prosperous Ifa year. )Aṣẹ.

Read More »

Awure ki Ori gbe ni:

Awure ki Ori gbe ni: Ori mi gbe mi re Ilu Ilaje Ibi kedere ni Ela gbemi lo Ori gbemi re Ilu Ilaya Ibi kedere ni Ela gbemi lo Sebi Iregbogbo lo n so ju Aje Iregbogbo ni se oju ...

Read More »

Gbogbo oju to nwo aworan yi…

Gbogbo oju to nwo aworan yi eni wole aisan won ni tayin lofa aburu ooo ao ni ri ogun ada njinan ooo !! Ase !

Read More »

Grandson Blows Hot Again! Hotter Actually!!

Lets hear your thoughts in the comment box bellow.

Read More »