Mo setán láti kú’ – Tems Mary Fágbohùn Olorin Naijiria olugbafe eye Grammy, Temilade Openiyi, ti a mo si Tems, ti safihan pe oun setan lati doju ko saare nigba ti oun fi eya orin takasufe ti gbogbo eniyan mo ...
Read More »Bí Ẹ Bá Rí Ilá L’ọ́jà Kí Ẹ Ma Rà Fún Mi
Mo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹBí ẹ bá rí ikàn l’ọ́jà kí ẹ ma rà fún miMo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹAtẹ̀gbẹ̀ tí o bá délé Olódùmarè kí o ra ọmọ wẹrẹ wá fún ...
Read More »Ọkùnrin tí àwọn adigunjalè yìnbọn mọ́ ní ọjà Bodija ṣì wà láyé — Ọlọ́pàá
Fẹ́mi Akínṣọlá Ìròyìn òkèrè, bí ò lé, a dín.Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti ṣàlàyé bí ìdigunjalè kan tí ìròyìn sọ pé ó gba ẹ̀mí èèyàn kan ṣe wáyé ní ọjà Bódìjà nílùú Ìbàdàn. Agbẹnusọ iléeṣẹ́ ọlọ́pàá, Adéwálé Òṣífẹ̀sọ̀, sọ nínú ...
Read More »Ede Abinibi
Orun Ire Ooooo
ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.
Read More »Ìpèníjà Baba Sùwé bè̩rè̩ nígbà tó pàdánù O̩mo̩ladun rè̩
Yínká ÀlàbíYoruba bo̩, wo̩n ni “aisan lo se e wo, a ko ri ti o̩lo̩jo̩ se”. Ko ki n se iroyin mo̩ pe iku ti poju gbajugbaja osere ori itage de ni o̩jo̩ aje o̩se̩ yii. Agba osere yii fi ...
Read More »Arápájà di Igbákejì Alága ẹgbẹ́ PDP níhà Gúúsù Orílẹ̀ yìí
Arápájà di Igbákejì Alága ẹgbẹ́ PDP níhà Gúúsù Orílẹ̀ yìí Ọrẹ Akínṣọlá Ṣé bóṣe wu Ọlọ́run Ọba ní-ín sọlá, èèyàn tó bá wù Ú ní-Ìn ṣe lógo.Igbákejì gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ nígbààa kan, Ọ̀gbẹ́ni Taofeek Arapaja, ti jáwé olúbori sípò Ìgbákejì ...
Read More »ÉÉPà Omi O!!!grand Finale, Yemọja ÒGùnlẹ́kí – Pópó Yemọja, Ìbàdàn
A dúpẹ́ púpọ̀ lọ́wọ́ Baálẹ̀ Yemọja, Ìyá Omítọ̀nàdé, Ẹbí, Ará, gbogbo Àgbà àti Ọmọdé… Ìbà Olódùmarè, ọdún pé, ọdún jọ. .To all friends, fans and well wishers, we’re grateful.
Read More »Ọlọ́pàá ò lè dáwa lọ́wọ́kọ́ àti sèwọ́de àyájọ́ EndSARS, -Oduala
Ọlọ́pàá ò lè dáwa lọ́wọ́kọ́ àti sèwọ́de àyájọ́ EndSARS, -Oduala Ọrẹ Òtítọ́jù Ọ̀kan nínú àwọn tó ṣagbátẹrù ìwọ́de ta ko àwọn ọlọ́pàá SARS t’íjọba ti fòfin dè, Bọlatito Oduala, tí ìnagijẹ rẹ̀ ń jẹ́ Savvy Rinu ti sọ pé kò ...
Read More »Awon omo Alade yari: Yoruba fe gba’ra re lowo ajeji Fulani to n tele basubasu
Akeredolu yari kanle. Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe… . Akeredolu yari kanle. Olubadan ni ki Seriki Sasa fi owo sibi owo o gbe. Gani Adams n yona lenu lori laasigbo Wakili. Sunday Igboho si ...
Read More »