Home / Iroyin Pajawiri (page 55)

Iroyin Pajawiri

Àwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won.

Àwon òrébìnrin tí ó lóyún ní ìgba kan náà ni won ya àwòrán pèlú oyún won. Eléyìí ma ti è wuni won sì rewà pèlú oyún won papò. Mo ro wípé oyún kìí mú àwon èlòmíràn rewà ni, bí ti ...

Read More »

Iyabo Ojo dùn nínú aso tí kò bo ìdodo (crop top) tí ó wò.

Ògbó-n-tarìgì òsèré, Iyabo Ojo ti gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti àwòrán ara rè nígbà tí ó ti pé ogójì odún tán , ó sì tún fi hàn wípé dunú. Òsèré Iyabo Ojo, yó se ayeye ogójì (40) ...

Read More »

Gomina Obiano lo kí Ààre Buhari ní Abuja léyìn tí ó gbégbà orókè níbi ètò ìdìbò tí won sèsè dì tán ní Anambra.

Gómìná ti ìpínlè Anambra tuntun, Gómìnà Willie Obiano ní ojó etì (Friday ) ti lo kí Ààre Muhammadu Buhari ní ilé-ìjoba ní ìlú Abuja. Obiano ti dúpé lówó Buhari nítorí kò se àgàbà-n-gebè níbi ètò ìdìbò tí ó kojá ní ...

Read More »

Arábìnrin yí ni ó jí èro ìbánisòrò ogbòn (30) tí ó sì ko pamó sí inú kómú àti pátá rè.

Arábìnrin yí ni ó jí èro ìbánisòrò ogbòn (30) tí ó sì ko pamó sí inú kómú àti pátá rè. Odóbìnrin tí a kò mo eye tí ó su ú, ni ó jí ju èro ìbánisòrò ogbòn lo tí ó ...

Read More »

Nabila Fash kúnlè Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won.

Nabila Fash kúnlè Oritsefemi oko rè nígbà tí ó fón Dólà si l’ára ní ibi ayeye kí ó tó di ojó ìgbeyàwó won. Ìyáwó Oritsefemi, Nabila, wà ní orí ìkúnlè níwájú oko rè nígbà tí ó bá Dólà fun níbi ...

Read More »

Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí ológun yí àti òdóbìnrin tí ó pàdé lórí èro ayélujára (Facebook) ya.

   Isé rí èro ayélujára n se kojá òye èdá… Àwon oko pèlú Aya àfésónà yí ti setán láti di tokotayà ní òsè péréte si léyìn tí won làdé lórí èro ayélujára (Facebook). Gégé bí Ijeoma Nwosu se so, ó ...

Read More »

Flavour àti àwon omo rè obìnrin méjì, Sophia àti Gabrielle Okoli ti ya àwòrán tí ó ya ni lénu .

Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé èyí tí a mò sí Flavour ti gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán àwon omo rè tí ó pè ní olorì, nígbà tí ó se ayeye ojó ìbí rè pèlu Sophia àti Gabrielle.

Read More »

Àwòrán Yvonne Nelson àti Jamie Roberts, bàbá omo rè níbi tí won tí n fi ìfé hàn sí ara won.

   E wo àwòrán èyí tí ó fi ìfé hàn láàrin olólùfé méjì, ògbóntàrigì òsèré orílè èdè Ghana Yvonne Nelson pèlú bàbá omo rè tí ó jé ayà àwòrán láti orílé èdè Britain. Jamie Robert wo okò òfuruufú láti lo ...

Read More »

Omobìnrin kan ní ilè Akwa Ibom ni àwon ebí rè ti fi sílè fún ikú sùgbón olùrànlówó kan ti gbà á kalé.

    Àwon òsìsé tí ó ranilówó láti orílè èdè Denmark àti olùdásílè ètò ìsàkóso àwon èwe (Children’s Aid Education and Development Foundation (ACAEDF), Anja Ringgren lovên, ti ran omobìnrin odún méwàá lówó, omo tí a mò sí Deborah, èyí ...

Read More »

Arákùnrin kan ní Bayelsa ti se oúnje sí eran Anta tí ó pa.

Arákùnrin kan tí ó wá láti Yenegoa ní ìpínlè Bayelsa, Bogilizibe Godwin Obiene, ti gbèrò láti se obè aláta yéríyérí abó kan léyìn ìgbà tí ó pa eran afayàfà tí ó je. Arákùnrin tí inú rè n dùn yí pin ...

Read More »