Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o ...
Read More »
Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o ...
Read More »Ṣé ó tọ́ kí Ojúlówó ọmọ Yorùbá ó torí pé òun di ipò Òṣèlú mú ó máa nawọ́ láti gbọwọ́ pẹ̀lú Ọba Aládé ní gbàgede?
Read More »Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ...
Read More »Odun Thaipuisam je orisii odun kan ti awon elesin Hindu ti won gbe ni Guusu apa orileede ile India ma n se. Ninu odun yii ni awon eniyan ti maa fi irin sonso orisiirisii gun ara won ni gbogbo ara. ...
Read More »Lojo Satide to koja yii ni CBS RADIO ranse pe Rihanna, ogbontarigi akorinbirin ile America. Ariya to waye ni Hollywood Bowl to wa ni Los Angeles ni won se lati fi se igbonlongo wi pe awon obirin le segun aisan ...
Read More »Joojumo loyun Kim Kardashian n ga sii. Yato si wi omobirin onibadi olokiki ilu Amerika naa kunra ju ti tele lo, ewa re si wa sibe digbi. Bakan naa ni awon imura re ko fi bee yato si awon aso ...
Read More »Awon omo orileede Iraq ti won sin orisii esin musulumi kan ti n je “Shia Islam” n fi obe ge awo ori ara won nibi won ti n gbadura.
Read More »