Ìròyìn tó bá ọ̀pọ̀ lẹ́jafùú ni ìròyìn ‘Mo ti ní àrùn Coronavirus’ èyí tí Gómìnà Ṣèyí Mákindé gbé jáde ní ọjọ́ Ajé lójú òpó twitter rẹ̀. Níbáyìí tí ó ti lo ọjọ́ méjì ní ìgbélé lẹ́yìn ìkéde yìí, gómìnà ìpínlẹ̀ ...
Read More »Mo Ti Fi Ẹjọ́ Abani Lórúkọjẹ́ Tó Fẹ́ Fi Àwòrán Ìhòòhò Mi S’órí Ìtàkùn Àgbáyé Sun Ìjọba – Waka Queen
À fi kí Ọlọ́run gbani lọ́wọ́ ẹni tó ń ṣọ́ni tá ò ṣọ́ o, ló dífá fún kójú má ríbi,gbogbo ara lòògùn rẹ̀, bí gbajúgbajà olórin wákà, Salawa Abẹni ti sọ pé, òun ti fi ẹjọ́ abani lórúkọ je tó ...
Read More »Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirus
Ogún ènìyàn jàjà bọ́ lọ́wọ́ coronavirusÌròyìn láti ọwọ́ Yínká Àlàbí Ni ipinle Eko ni ori ti ko ogun eniyan yo ni ile iwosan ti won ti n toju awon ti kokoro Covid-19 n ba ja. Bi o tile je pe ...
Read More »Ronaldinho Ń Kó̩ Is̩é̩ Gbé̩nàgbe̩nà Nínú È̩wò̩n Ní Orílèèdè Paraguay
Ogbontarigi ninu boolu alafesegba to je omo bibi orileede Brazil ti o si ti fi igbakan ri je eni akoko ninu boolu alafesegba kaakiri agbaye, Ronaldinho,
Read More »Àfàìmọ̀ Kí Coronavirus Má Dà Bí I Ti China Tabi Italy- Mínísítà Kìlọ̀
Ẹni mẹ́rin mì ìn kó àrùn apinni ní mímí èèmii coronavirus ní Nàìjíríà,àfàmọ̀ kò mọ́ dà bí i ti China,l Italy— Mínísítà kìlọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Ìgbọrọ̀ sàn ju ẹbọ rúrú fún ẹni tó bá fẹ́ gbọ́ ni o.Ó ti di ...
Read More »Àwọn Fíìmù Òde Òní Ń Kọ́mọ Lólè Àti Ọ̀pọ̀ Ìwà Burúkú – Iyabo Ogunsola
Àwọn fíìmù òde òní ń kọ́mọ lólè àti ọ̀pọ̀ ìwà burúkú Fẹ́mi AkínṣọláṢé àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní ẹgbẹ́ burúkú ba ìwà rere jẹ́. Ajíyìnrere Felicia Iyabode Ogunsola tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Efúnsetán Aníwúrà, Ìyálọ́de ìlú Ìbàdàn nínú eré, ...
Read More »Fayemi, ilẹ̀ Oòduà (Yorùbá) kìí ṣe Kano tí wọn ti ń yọ Emir lórí oyè… Alaafin
Àwọn ọmọ Nàìjíríà lórí ojú òpó ìkànsíraẹni Twitter ti dásí ọ̀rọ̀ láàrin Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti, Kayode Fayemi àti àwọn ọba ní ìpínlẹ̀ náà. Èyí kò sẹ́yìn lẹ́tà tó jáde lórí ẹ̀rọ ayélujára níbi tí Aláàfin Ọ̀yọ́, Ọba Lamidi Olayiwola Adeyemi ...
Read More »Ọba mẹ́wàá, ìgbà mẹ́wàá
Awon onpitan wu itan Emir Kano ana jade. Won ni oro re dabi egun ti baba baba re ti se sile. Won ni odun 1963 ni ede aiyede waye laare Emir Mohammed Sanusi to je baba eni ti gomina yo ...
Read More »Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn
Àwọn obìnrin tọ́kasí pàtàkì ìbáraẹnidọ́gba láárin ọmọnìyàn Ọjọ́ kẹjọ ọdọọdún ni àyájọ́ àwọn obìnrin lágbàáyé níbi tí gbogbo àgbáyé tí ń kọjú sí àwọn obìnrin láti yòǹbó àwọn iṣẹ́ takuntakun tí wọ́n gbé ṣe láì nọ́ọ́ní onírúurú ìpèníjà, ẹ̀dùn ọkàn ...
Read More »Ènìyàn mó̩kàndínlógójì ti ní àsepò̩ pèlú alárùn coronavirus l’Ogun
Iberu bojo ti po gan-an ni ipinle Ogun bayii, paapaa julo lati igba ti ayewo ti fihan pe alarun buruku kan ti wo orileede yii lati orileede Italy.
Read More »