Kofi 19 dẹ́yẹ sí ìpínlẹ̀ Kogi àti Cross River –Osagie Àwámárídìí ni iṣẹ́ Elédùwà, ṣùgbọ́n ọmọ èèyàn lọ́pọ̀ ìgbà má a ń fẹ́ tú fín ìn ìdí i kóòkò láti mọ kín gán án ní ń gbénú-un rédíò fọhùn. Bí ...
Read More »Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC
Ènìyàn 148 míràn lárùn Covid-19 ní Nàìjíríà–Àjọ NCDC Ó ti pé ẹgbẹ̀rún mẹ́ta àti márùndínládọ́jọ èèyan tó ti ní àrùn apinni léèmí yìí ní Nàìjíríà. Ìpínlẹ̀ Èkó ló ṣì ń léwájú.Ní bí a ṣe ń kó ìròyìn yìí jọ. Iye ...
Read More »Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ wọ ìbòmú tàbí kí ẹ rugi oyin – Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Ọlọ́pàá èwo n tèpè ni àṣà tó gbayé kan tẹ́lẹ̀ , ṣùgbọ́n ní àsìkò kòró yìí, ó dà bí ẹni pé wọ́n ti sún ilé iṣẹ́ ọ̀hún kan ògiri ...
Read More »Kòrónáfairọ̀ọ̀sì kò dí ìgbáradì ètò ìdìbó ìpínlẹ Edo àti Òǹdó lọ́wọ́–INEC
Ó dà bí ẹni pé ń tí ń ṣe Lébáńdé kò s’ọmọ rẹ o, Lébáńdé ń sunkún ọmú, ìyá rẹ ń sunkún ebi, ló díá fún bí àjọ elétò ìdìbò Nàìjíríà ti kéde pé àjàkálẹ̀ àrùn apinni léèmí coronavirus kò ...
Read More »Aye̩ye̩ o̩jó̩ò̩bí Sikiru Lemon
Aye̩ye̩ o̩jó̩ò̩bí Sikiru LemonBí a bá dájó̩, o̩jó̩, á pé, bí a dósù, osù á kò. Gbogbo o̩jó̩ ko̩kàndínló̩gbò̩n, osù ké̩rin o̩dún ni o̩jó̩ò̩bí Alhaji Sikiru Lemon. Yorùbá bò̩,wó̩n ní “àìbá wo̩n sí níbè̩ ni àìbá wo̩n dá síi”. Ìwé ...
Read More »Olò̩tè̩ èmi àti Aláàfin máa fojú ba ilé-e̩jó̩ – Wasiu Ayinde
Gbajugbaja olorin fuji ti ina orin re si n jo lowo bayii ni o ti fa ibinu yo nigba ti won fesun kan an pe, o ni asepo pelu okan ninu awon olori Alaafin ti ilu Oya, Oba Lamide Adeyemi ...
Read More »Maryam Sanda ṣì wà lẹ́wọ̀n, Buhari kò dáa sílẹ̀.
Iléeṣẹ́ Ààrẹ ló sọ pé Ìròyìn tó ń jà rànyìnrànyìn kiri pé Ààrẹ Muhammadu Buhari tí darí jin arábìnrin náà kìí ṣe òtítọ́ rárá.Ki àwọn èèyàn kọtí ọ̀gbọin sí i.Ní oṣù kínní ọdún yìí ni ilé ẹjọ́ dá arábìnrin Maryam ...
Read More »Èmi kò ní àrùn coronavirus – Yahaya Bello
Gomina ipinle Kogi,Ogbeni Yahaya Bollo lo n forere lori ero ayelujara pe ki won se fi orokoro ko oun lorun, oun lo ni arun covid-19 gege bi awon oloselu Kan se n gbee kiri. O ni loooto ni adari aabo ...
Read More »Ilé-ìwé Chrisland s̩e ìrànló̩wó̩ fún àwo̩n tó kù díè̩ fún l’Ekoo
Aiba won si nibe ni aiba won da sii. Eyi lo mu ki Alaga ile-iwe ati oludari, Mama Winfrey Awoshika ati Ibironke Adeyemi pese iresi, ewa, gaari ati ororo repete fun awon ti o ku die fun ni awujo.
Read More »Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ Oyo
Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ OyoÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Akoko Technical University to fi ikale si ilu Ibadan se bebe ni irole ana. Won pese aso ibomu ara otun fun ijoba ipinle Oyo. ...
Read More »