Home / Tag Archives: iroyin (page 9)

Tag Archives: iroyin

Ó di láyéláyé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè

Ó di láéláé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè Gbajúgbajà òṣèré Samuel Akinpẹlu tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àlàbí Yellow ti jẹ́ Ẹlẹ́dàá nípè. Akọni tí à ń perí yìí jẹ́ òṣèré tí àwọn èèyàn kò ...

Read More »

Àlùfá tọ́ bá ọmọ ọdún méje sùn, wẹ̀wọ̀n ọdún Márùn- ún ní ìpínlẹ̀ Ekiti

Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n t’olóhun.Ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti tífìtàn balẹ̀ bí wọ́n ṣe jẹ́ ìpínlẹ̀ àkọ́kọ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ láti máa dárúkọ ọ̀daràn afipá bánilòpọ̀ hàn àti láti máa dójú tì wọ́n. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Kayode Fayemi gbé ...

Read More »

Àhes̩o̩ ò̩rò̩ ni ikú Babangida

Aheso oro ni iku BabangidaYinka AlabiAriwo iku ajagunfehinti to o tun je Aare Ologun ni orileede yii tele ri, Ibrahim Babangida ni o gbode Kan.Ariwo yii po lori ero ayelujara lati idaji oni sugbon Ogbeni Kazim Afegbua ni iro ni. ...

Read More »

Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́

Iléeṣẹ́ DSS tú Sowore sílẹ̀ lẹ́yìn ọjọ́ gbọọrọ ní àhámọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn òṣìṣẹ́ DSS gbé Soworẹ lásìkò tí ó fi ń léwájú ìwọ́de “Revolution now”.Ìtúsílẹ̀ rẹ̀ ń wáyé lẹ́yìn tí ó ti lo ọjọ́ márùndíláàdóje ní hàhámọ́ àwọn DSS. ...

Read More »

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba – Seyi Makinde

Màá ṣa ipá láti mú káwọn aráàlú nígbẹkẹ̀lé nínú ìjọba Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ̀,wọ́n ní ,bí Ọlọ́run bá rí ọ, jéèyàn náà ó sẹ̀ríìrẹ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí,bí Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti fọwọ́ gbáyà pé òun ...

Read More »

Kogi àti Bayelsa ìdìbò gómìnà gbọdọ̀ lọ nírọwọ́ rọsẹ̀.. ..Ààrẹ Buhari

Kogi àti Bayelsa ìdìbò gómìnà gbọdọ̀ lọ nírọwọ́ rọsẹ̀.. ..Ààrẹ Buhari Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé ko ko ko là á ránfá adití,àti pé ó ń bọ̀, ó ń bọ̀,ojú ni wọ́n ń mú tó o. Èyí ló mú kí Ààrẹ orílẹ̀ ...

Read More »

Kùkùlajà Ètò Ààbò, Gani Adams Ní OPC Àtàwọn Míì Ṣetán Láti Ṣiṣẹ́ Pẹ̀lú Àwọn Òṣìṣẹ́ Elétò Ààbò Nílẹ̀ Oòduà (Yorùbá)

http://iroyinowuro.com.ng/2019/11/10/kukulaja-eto-aabogani-adams-ni-opc-atawon-mii-%e1%b9%a3etan-lati-%e1%b9%a3i%e1%b9%a3e-pelu-awon-o%e1%b9%a3i%e1%b9%a3e-eleto-aabo-nile-yoruba/ Kùkùlajà ètò ààbò,Gani Adams ní OPC àtàwọn míì ṣetán láti ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn òṣìṣẹ́ elétò ààbò nílẹ̀ Oòduà (Yorùbá) Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé Oòduà (Yorùbá) bọ̀ wọ́n ní ọmọ onílùú kìí fẹ́ ò tú. Gbogbo áwọn àgbààgbà nínú ẹgbẹ́ ajìjàgbara ...

Read More »

Ọrẹ Fálọmọ , Irúnmọlẹ̀ Ìṣègùn Tó Dáńtọ́ Nínú Ìràn Oòduà(Yorùbá) Wọ Káàlẹ̀ Lọ

Ọrẹ Fálọmọ , irúnmọlẹ̀ ìṣègùn tó dáńtọ́ nínú ìràn Oòduà(Yorùbá) wọ káàlẹ̀ lọ Fẹ́mi Akínṣọlá Hùn! Báakú làá dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè. Ni báyìí, gbogbo ọmọ Oòduà(Yorùbá) ló tí ń sun rárà ọlọ́kan ọ̀ jọ̀kan lẹ́yìn in Dókítà Ọrẹ Fálọmọ ...

Read More »

Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ

Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Seyi Makinde ti se àbẹ̀wò sí ilé Ọlọrẹ tó wà ní àdúgbò Ọ̀jọ́ nílùú Ibadan .Bẹ́ẹ̀ bá gbàgbé, ilé yìí ...

Read More »

Àṣírí Pásìtọ̀ Tó Ń Fí Sọ́ọ̀si Ṣe Ọ̀gbà Wèrè Tú

Àṣírí pásìtọ̀ tó ń fí sọ́ọ̀si ṣe ọ̀gbà wèrè tú Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé biribiri òkuǹkùn ọ̀rọ̀ lójú ọmọ aádámọ̀ ,ìmọ̀lẹ̀ gbòò ni lójú Adẹ́dàá. Ní báyìí, Olùsọ́ àgùtàn Joseph Ojo, ní ọwọ ṣìnkún ọlọpàá ti mú fún lílo ilé ìjọsìn ...

Read More »