Home / Test2page 112

Test2

Fi ere si temi Eledumare

Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe ...

Read More »

Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !

Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun ...

Read More »

Oba Erediauwa Ti Waja

Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. ...

Read More »

Awon osu ni ede Yoruba (12 Months of the Year in Yoruba Language)

E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu December -Ope.

Read More »

Aderupoko lori Eto Gbajumo Osere

Read More »

Bobo B lori Eto Gbajumo Osere

Read More »

YORÙBÁ DÙÚN KÀÁÁÁ

A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E ...

Read More »

Olojo Ibi

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa TUNRAYO IBRAHIM ti won je okan pataki ninu ebi Oodua Rere. Iyalode olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...

Read More »

Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?

Ebeere Toni: Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?  

Read More »

Iwure Owuro Toni: 24-04-2016

E MAA WI TELE MI : …… *Ade ogo mi ko ni si danu. *Aso iyi, aso eye mi ko fa ya. *Edumare ma je ki n fi ota se ore. *Oluwa dakun so egan mi dogo. *Edumare wa so ...

Read More »