Oruko Kan Fun Iya omode yii ?
Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?
Read More »
Eyin Eniyan mi Eje Kia Rerin die. Oruko kan fun iya omode yii ?
Read More »Eku Dede asiko yio eyin eniyan Atata tin GBE inu ilu Yoruba Atata, oro tonlo Lowo bayi ni mo muwa oro elo obe to won gogo yi ma ni mofe kia soro Lorie o. E wo tomato timo ra ni ...
Read More »Nje Iwo leso “FACEBOOK PASSWORD” re fun Ololufere????? Huuum ema paro ooo
Read More »Ko so’ogun mo bee si ni ko so’ote mo ni igbeyawo eleyi ti o ku die ko dojubole. Oserekunrin Afeez Abiodun “Afeez Owo” ati iyawo re Oserebinrin Mide Martin ni ti mu ife won padabo sipo. Laipe yi ni edeaiyede ...
Read More »E MAA WI TELE MI : ….. *Fitila ogo mi ko ni ku. *Aso iponju ko ni se dede orun mi. *Oluwa ba mi segun ota ile. *Edumare ba mi segun ota ode. *Ina omo ko ni jo mi. *Ina ...
Read More »Lobinrin wa se dada laji bii.. Adupe lowo OLODUMARE too mu emi ati iwo losii ipo oku lati ano too tun jiwa pada saiye, si aye rere nitori gbogbo eni bati sun ti oku ope ni fun ODUMARE.. Moo wa ...
Read More »Hummm wo oremi banuso mobayan so tori inu jin. # wo Opolopo ore lo nfara han gegebi ota Oplopo ota naa losi nfi ara han gegebi ore….. # nje Otie mo pe opo alangba lo dankun dele ao kuku mo ...
Read More »ORIN : “E bami KIRA fun #Mama mi.. #Orisa bi #IYA o.. Ko si Laye… …………….. Iya mi.. Abiyamo lojo Ogun le.. Abiyamo Oloja Aran Abiyamo tii fojooumo wa ko le Dara fun Omo… …………………… Ki Emi gbogbo Awon #IYA ...
Read More »E MAA WI TELE MI : …….. *Oluwa gba eru iya lori mi. *Edumare ma se je ki n seru egbe. *Oluwa taari alaanu si mi. *Edumare fiso re so mi. *Oluwa pase irorun sinu aye mi. *Iku aitojo ko ...
Read More »ojuluoooooooo! owe ni oro-aye, A NLO SI OYO O KOJU SI OYO A TUN BO LATI OYO OYO NAN LO TUN KOJU SI. SE BI ILU-GANGAN. iyen nipe ORUN LATI WA ORUN NAN LAO PADA SI. iku pa ABIRI o ...
Read More »