Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !
Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun ...
Read More »
Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun ...
Read More »Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. ...
Read More »E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu December -Ope.
Read More »A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E ...
Read More »Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa TUNRAYO IBRAHIM ti won je okan pataki ninu ebi Oodua Rere. Iyalode olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...
Read More »Ebeere Toni: Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?
Read More »E MAA WI TELE MI : …… *Ade ogo mi ko ni si danu. *Aso iyi, aso eye mi ko fa ya. *Edumare ma je ki n fi ota se ore. *Oluwa dakun so egan mi dogo. *Edumare wa so ...
Read More »mo de werewere bi eji-ale mo de warawara bi ti iyaleta, ewe-itu lo ni ke tu mise ewe-iifa loni kefa mi mora, toripe enikan ki so okun mo igbin lorun, won ki fi pakute mu eja l’odo, beni omode koni ...
Read More »