Igbeyawo Ooni Ile-Ife fo yangayanga?
*Oba Ogunwusi n mura lati se igbeyawo tuntun Lose to koja ni awon aheso oro kan be sile nigboro eleyii to ti bere si ni mu awuyewuye lowo bayii. Lara awon oro naa ni eyi ti n wi pe, ...
Read More »
*Oba Ogunwusi n mura lati se igbeyawo tuntun Lose to koja ni awon aheso oro kan be sile nigboro eleyii to ti bere si ni mu awuyewuye lowo bayii. Lara awon oro naa ni eyi ti n wi pe, ...
Read More »“Ilaji owo osu won nijoba yoo ma yo fi san gbese naa” -Komisanna isuna owo Gomina Ayodele Fayose ti yanda owo to le ni igba milionu owo naira (N236,860,000) gege bi owo ti won ya soto lati ya awon osise ...
Read More »*Femi Adebayo n wonu oselu lo diedie Nibayii, gomina ipinle Kwara, Abdulfatah Ahmed, ti yan ogbontarigi onisetiata, Femi Adebayo, gege bi oluranlowo pataki nipa ise ona, asa ati irinajo-afe (Special Assistant on Arts, Culture and Tourism). Osere ti inagije re ...
Read More »*Won ni ki won yegi fun un leyin to pa omo ijo re Reverend King Opin irin ajo ti de ba Rev. Chukwuemeka Ezeugo ti inagije re n je Reverend King nigba ti ile ejo to gaju yan-anyan, Supreme Court, ...
Read More »Ogbeni Samuel Omosaba, eni odun mejilelogoji (42), ni owo awon olopaa ipinle Ondo ti te bayii pelu bo se ge ori omobirin, eni odun meta (3), to je omo aburo re lati fi sogun owo ojiji. Isele yii lo waye ...
Read More »*Won ti dajo iwuye Adetunji gege bi Olubadan tuntun Gege bi oro awon Yoruba to wi pe, ti oba kan ko ba ku, oba mi ki i je. Eleyii ni awon igbimo Olubadan tile Ibadan tele pelu bi won se ...
Read More »Arambara aso oge mbe lowo Beewealth-Textiles!
Read More »Minisita fun eto ilera, Ojogbon Isaac Adewole, ti se idaniloju alaye wi pe, efon abami ti n sokunfa kokoro Zika ti ko gboogun ti wa ni Naijiria. Bakan naa lo si ro awon eniyan lati se ohun gbogbo ni ikapa ...
Read More »Awon foto re wa nisale
Read More »*Mimiko ya bilionu meedogun soto lati san gbese Lose to koja ni awuyewuye kan tun seyo nipinle Ondo nigba ti egbe oselu APC tako Gomina Olusegun Mimiko ti ipinle naa nipa bo se ya bilionu meedogun ati milionu mejo (N15. ...
Read More »