Home / Test2page 143

Test2

E wo ohun ti Gomina Fayose n se laaarin oja

Gomina Ayodele Fayose da moto re duro loja Bisi to wa ni Ipinle Ekiti lati teti si edun okan iya arugbo yii nipa ohun ti won fe ki ijoba o se fun won.  Gomina fara bale lati gbo gbogbo ohun ...

Read More »

Igbe aye Oba Lamidi Olayiwola Atanda Adeyemi dun bi oyin

Laipe yii ni Oba Lamidi Adeyemi, Alaafin Oyo pe eni odun metadinlogorin. E le ka iroyin naa nibi: Lara awon foto ojo ibi baba mi-in to te wa lowo ni eyi ti baba ya pelu Olori Badirat Adeyemi, olori baba ...

Read More »

Iyanu sele leyin odun meta  

Odun meta lo gba arakunrin yii lati yii igbe aye re pada si bo se fe. O salaye wi pe alaafia ti de ba ara oun bayii, oun le mi daada bakan naa ni oun jafafa ju ti tele lo. ...

Read More »

Foto tuntun: E wo ohun ti Mikel Obi n se loju titi

Mikel Obi ati iyawo re, Olga pelu awon omo ibeji. #EbiAlayo

Read More »

Awon egbe APC ti ko lati mu ileri won se #Our5K

Nje e ti gbo? Awon omo ile igbimo asofin agba l’Abuja ti won je ti omo egbe APC ti tako aba eleyii to wa nibamu pelu ileri ti Aare se lati maa san egberun marun-un owo naira (5K) fun awon ...

Read More »

“Ni Akute, awon ota ni won ba Amosun loruko je” Ijoba ipinle Ogun

Olayemi Olatilewa Ile ise ijoba ipinle Ogun ti pe akiyesi awon ara ilu si iroyin eleje kan ti iwe iroyin kan gbe jade wi pe wahala wa laaarin awon oloja ti won gbe ni agbegbe Akute ati gomina ipinle Ogun, ...

Read More »

Iwon ese bata kan pere: E kaabo sinu osu tuntun

#Ogulutu #4 Eyin eniyan mi, n maa ki yin kaabo sinu osu tuntun pelu itan Ogbeni Darby omo ilu Amerika to ti n tawo-tase ninu mi fun igba pipe. Itan aroko ko, bee si ni mi o ni fe ki ...

Read More »

Awon olopaa ti mu omo yahoo-yahoo niluu Ogbomoso

OlayemiOlatilewa Owo awon olopaa kogberegbe ti ipinle Oyo ti te onijibiti ori ero ayelujara, Babatunde Fatai niluu Ogbomoso. Tunde to je omo asese jade ileewe Ladoke Akintola University of Technology, eleyii to kale siluu Ogbomosho to wa nipinle Oyo ni ...

Read More »

Niluu Ilorin: “Awon osise mefa ti ku, awon kan wa nile iwosan”- Akowe egbe osise

Awon osise ajo olomi ti ipinle Kwara tu jade lojo Isegun to koja yii niluu Ilorin nigba ti won fi ehonu won han nipa owo osu won eleyii ti ijoba ipinle naa ko lati san lati inu osu keje seyin. ...

Read More »

Won o je ki Saraki o rona gba leyin to fun awon minisita Buhari lona lo

Olayemi Olatilewa Ile ejo kotemilorun to kale siluu Abuja ti da esun aare ile igbimo asofin agba, Bukola Saraki nu patapata. Ninu esun ti Saraki gbe lo si ile ejo, ibe ni Saraki ti n ro ile ejo lati pase ...

Read More »