Ojo-ibi oniroyin to gbamuse: Femi Davies, okunrin ogun
Oni ni ojo ibi Ogbeni Femi Davies, alase ati oludari MetroNews Nigeria. Igba odun, odun kan ni.
Read More »
Oni ni ojo ibi Ogbeni Femi Davies, alase ati oludari MetroNews Nigeria. Igba odun, odun kan ni.
Read More »Awon omo Yibo ti bere si ni soko oro si iran Yoruba to ri wi pe won fe pin kuro ninu orileede Naijiria. Won fe da Biafra sile, won ni awon ko ba Naijiria se mo. E dakun, e wo ...
Read More »Leyin ti awon omo ologun yinbon pa okan lara awon oluwode ti won pe fun idasile Biafra, ibon tun ba okan lara won lonii niluu PORT HARCOURT.
Read More »Ilu Amerika ti gbalejo Aare ile Naijiria nigba kan ri, GOODLUCK JONATHAN si Challotsville to wa ni Virginia latari igbelaruge ijoba awarawa re ati gbigbe ijoba sile ni woorowo. Ogbeni Jonathan lo sokale siluu Amerika lojo aje ana. Lati Ọwọ ...
Read More »Awon Yoruba ni ti ogun eni ba daniloju, eniyan fi i gbari ni. Ile ise China kan ti n se foonu, OUKITEL, ti kede wi pe, eni ba foju ana wo eegun, ebora nii boru won laso. Won ni to ...
Read More »E gbo, taani igo rewa ju loju re? Se Toyin ni abi Muyiwa Ademola, abi Eniola nigo naa ye ju?
Read More »#Our5K ti da wahala sile lori ayelujara: Ile Igbimo Asofin ni wahala naa ti bere Olayemi Olatilewa Lojo Wesde to koja yii nile igbimo asofin agba to kale siluu Abuja gbegi dina sisan owo egberun marun-un fun awon odo ile ...
Read More »Arabirin Moji Lawal, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ipinle Eko segbeyawo alarinrin lopin ose to koja yii pelu oko re, John Paul to je onisowo pataki. Arabirin Moji, eni to je obirin akoko ti o ma soju ekun ...
Read More »Gomina Ayodele Fayose da moto re duro loja Bisi to wa ni Ipinle Ekiti lati teti si edun okan iya arugbo yii nipa ohun ti won fe ki ijoba o se fun won. Gomina fara bale lati gbo gbogbo ohun ...
Read More »Laipe yii ni Oba Lamidi Adeyemi, Alaafin Oyo pe eni odun metadinlogorin. E le ka iroyin naa nibi: Lara awon foto ojo ibi baba mi-in to te wa lowo ni eyi ti baba ya pelu Olori Badirat Adeyemi, olori baba ...
Read More »