Maheeda di Pasito oloro itunnu
Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n ...
Read More »
Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n ...
Read More »Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi ...
Read More »Eyi ni fidio orin ewi lati owo Akeem Lasisi ti won pe akole re ni ELELETURE
Read More »Odun lo sopin, eni Edua Oke pamo nikan lo yege. Sugbon nipa temi ati awon ololufe mi, a ko ni padanu enikeni lase Eledumare. Ase Lori eyi ni i ti ma fi yin sile lati je igbadun orin Edaoto to ...
Read More »Okunrin olokada kan ti won pe oruko re ni Ibrahim ni won sadeede ba oku re loju titi laaaro yii ni agbegbe Alaba Suru to wa loju ona masose Badagry niluu Eko. Igba ti won yoo ye okunrin naa wo, ...
Read More »Davido ti se afihan foto re lenu irin ajo re silu London. Ninu atejade yii ni Omo Baba Olowo ti n so wi pe oun ti n sun mo ilu London. Eyin ara London, se e ti wa ni imurasi?
Read More »Gomina Ayodele Fayose se ayeye ojo ibi odun marunlelaadota (55) lonii ni Ipinle Ekiti. Akara oyinbo yii ni awon tisa fi da lola.
Read More »Fun awon omoge iwoyii ti won fe nirun gigun, ti yoo dudu kirimi ti yoo si ma dan bi koroshin, ti irun naa kosi ni maa ja butebute bi owu, ogun re niyii to daju bi ada. E wa ewe ...
Read More »Orisiirisii eniyan lo wa laye pelu agbara inu eleyii ti Oba oke da mo onikaluku won. Eyi ti Oluwa fun Bimbo Thomas lo je eyi to jo mi loju ju. Yato si wi pe Edua oke fun lebun ise tiata ...
Read More »