Ilééṣẹ́ Aṣọ́bodè Naijiria ń pa bílíọ̀nù N5.8 wọlé lójúmọ́
Ilééṣẹ́ Aṣọ́bodè Naijiria ń pa bílíọ̀nù N5.8 wọlé lójúmọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe n ta o ba fẹ ba fẹ o bajẹ, o ní ba a ṣe e ṣe e.N lo bi ọrọ kan ti ọ̀ga agba asọbode ilẹ yìí sọ ...
Read More »
Ilééṣẹ́ Aṣọ́bodè Naijiria ń pa bílíọ̀nù N5.8 wọlé lójúmọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe n ta o ba fẹ ba fẹ o bajẹ, o ní ba a ṣe e ṣe e.N lo bi ọrọ kan ti ọ̀ga agba asọbode ilẹ yìí sọ ...
Read More »Ìṣe èèyàn ,ìṣe ẹranko, Ìjàpá tó wà ní ààfin Ṣọ̀ún Ògbómọ̀ṣọ́ Alàgbà ti papòdà lẹ́ni ojilelọọdunrun ọdún ó lé mẹrin lóke eèpẹ̀ . Fẹ́mi Akínṣọlá Toyin Ajamu, to jẹ akọwe agba ni Ààfin Kabiyesi Ṣọun ti ilẹ Ogbomọṣọ ti bùn ...
Read More »My motherWho walks in the nightGraceful be thy stepsAs you place your heelOn the head Of a hidden Cobra And it cannot bite you.
Read More »“615”, ńọ́ń́bà tuntun fún ìdáàbòbò àwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Awọn agba bọ wọn ni oju bayii ni alakan fii sọri.Eyi naa lo mu gomina ipinlẹ Oyo,Ṣeyi Makinde gbe igbesẹ akin, ni bi o ṣe kede ńọ́ń́bà Ẹẹfa, ookan, ...
Read More »Arun iba buruku kan n da yanpon- yanrin sile bayii ni ile-ise awon obinrin (Queens college) to wa ni ilu Eko.Ironu ti dori awon agba kodo ni ipinle Eko bayii paapaa julo fun gbogbo awon to lomo nibe. Ile-iwe yii ...
Read More »Ṣàgbẹ̀lójú yòyò, ni ọ̀pọ̀ àwọn òṣèré…. òjòpagogo Fẹ́mi Akínṣọlá Awọn agba bọ,wọn ni purọ n niyi,ẹwu ẹtẹ nii da bolowo ẹ lọrun lo mugbajugbaja agba ọjẹ oṣere Yoruba, Razak Ọlayiwọla ti gbogbo eeyan mọ si Ojopagogo bi o se sọrọ ...
Read More »Ẹgbẹ ́Afẹ́nifẹ́re kọminú lórí ìwádìí ikú ọmọ Baba Faṣọranti to jẹ olori Afẹ́nifẹ́re – Odumakin Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà ní bí eyín bá n mì pẹkẹ pẹkẹ,erìgì ni kò fálẹ̀ mójúṣe rẹ̀.Ẹgbe Afenifẹre ti fi ero wọn han lori aijafafa ...
Read More »Ile-ejo giga to fi ikale si ilu Abuja lo pase fun ijoba apapo pe ki won yokun lorun Ogbeni Omoyele Sowore.Sowore ni o n gbimo lati se iwode Kan to maa mi ilu titi. Lati igba naa ni ijoba apapo ...
Read More »Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe aifẹsọ kebosi,lai rẹni jo o,ati pe n ta o ba fẹ o bajẹ,o ni bi o ṣe yẹ ka ṣe e,eyi lo bi atunse abẹnu lati fopin sawuye wuye to waye latari aawọ to suyọ laarin awọn ...
Read More »Ẹ jẹ ka jọ gbadura fun Ẹda Onile-ọla pe bi wọn ṣe ṣe tọdun yii ni wọn yoo ṣe tẹẹmi-in towo-tọmọ, ninu ilera pipe ati aiku ti i ṣe baalẹ ọrọ.
Read More »