Gómìnà ìpínlè Osun tí a sí Oyetola gba àwon èèyàn là nínú ìjàmbá okò tí ó selè ní òpópónà Ibadan sí Èkó.
Ókéré jù èèyàn tí ó kojá néjìlá ni ó fara pa nínú ìjàmbá tí ô selè ní òpópónà Ibadan lo sí Èkó sùgbón tí Gómìnà Oyetola ti gba wón kalè. Ògbéni Isiaka Oyetola náà n lo sí èkó ni ojó ...
Read More »
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà
