Home / Àṣà Oòduà / #Osunisholy

#Osunisholy

Ologbo se oro okije aresa se oro okije ase ije osun osogbo ni oni yi o emafi osun se ibaje eyin eni yan ibi ema ba olosun je osun ki se ote osun ki se ibaje tori idi eyi olosun ki lu jibiti ni agbara ni owo yeye mi adi eni. Unla emaje ki ama di ku eru eni ti ofuye ire ni oromi ati iwo yo jasi ooooo

 

Ore Yeye o! Oro gidi leyi o. Osun kii hu iwa buruku, Osun kii se abosi, Osun kii di ote, Osun kii jale, beeni Osun kii lu jibiti. Ki Olodumare f’owo tan okan awon asebaje! Omi tutu wa o nii di gbigbona! Aase!
Osun doesn’t support indiscipline: bad behaviours, insolence, conspiracy, greed, stealing and fraud. May Olodumare touch the hearts of the bad eggs! May our ever cool and serene waters never turn lukewarm and hot! Aase!

 

Cc – Osunlanu Yeyeluwa Olomitutu Worlwide

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Iya mi Osun Sengese

Iya mi Osun Sengese Ladekoju Ebora ti n gbenu omiLagbolodo,Iwo ni mo nkee si o.Osun ma n bo oYago lona o.