Home / Author Archives: ayangalu (page 44)

Author Archives: ayangalu

Iyawo re o, a mo eni towu oooo!

Owo idana o po ooo 5,000 pere ni oooooo

Read More »

N je e ran’ti iwe yii?

Read More »

Ijinle Ninu Oro Ifa Fi Ye Wa Nipa Bi Ila Se De Atelewo Wa.

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Ojó oni a san wa o ao ri tiwa se o ase. Gegebi awon opolopo eniyan se maa nsoro wipe “atewolabala ao meni to ko” lotito la ba ila latelewo wa sugbon imo ijinle ...

Read More »

Ifa Iwure Toni Jade Ninu Odu Ifa Ogundigara

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku aseku odun o emin wa yio se pupo re laye awon alaseku yio bawa se o, ako ni rogun inira o ase. Ifa iwure toni jade ninu odu ifa Ogundigara Ifa naa ki ...

Read More »

Eyelé kìí léegun ìsé lára …

Eyelé kìí rìnrìn ìyà l’ésè Eye tó bá ye làá pè l’éyelé. Good morning Universe!!! May the blessing of today abide with each and everyone of us. Ase!!! Popoola Owomide Ifagbenusola

Read More »

Olojo Ibi Toni – Arabinrin Adetona Banke

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Arabinrin Adetona Banke ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...

Read More »

Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016

Hummmmmm erora gbogbo yan ale yan ale Nje O mo wipe ohunti ntan lodun eegungun bi? Woo Orewa Kosi nkan towa nta ju ohun towa nile lo bi Iwo naa ba toju titie dada yio rewa yio wuyi loju Gbomi ...

Read More »

Awon ona wo ni a le gba lati gba ara wa si ‘le ni oko eru paapa ni owo awon oyinbo ati arabu?

English: What are the ways to free ourselves from the physical, mental and spiritual enslavement especially from the hands of Europeans and Arabs?   Cc – Omo Oba

Read More »

Odu Eji Ogbe

Ìpẹpẹrẹ ìmọ ni farabalẹ ni jogunda Adia fun Orunmila Ifa nlọ ba wọn mulẹ budo Nita Iku nita Arun, Nita Ajogun Mẹrẹrindilogun Te nbẹ lode oṣalaiye. Slender-Palm-Frond-is-Patient-In-Taking-Its-Revenge Revealed the way to Orunmila when he was looking for a place to ...

Read More »

Ará Ọ̀run

Cc – Moyo Okediji

Read More »