Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe Iroyin Owuro ose yii tun ti gori igba. Iwe iroyin ti n gbona felifeli. Die ni yii ninu awon koko ...
Read More »Ogulutu: Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata
#Ogulutu Nigba ti mo wa ni kekere, awon egbon adugbo kan wa, awon ti awon obi wa gba wi pe won nimo ju wa lo. Ti o ba ti n to akoko fun awon egbon ti wa lati wo ile ...
Read More »Ayeye Ojo Ibi Oba Lamidi
Oba Alhamis Olayiwola Atanda Adeyemi, Alaafin ti ilu Oyo, pe eni odun metadinlogorin (77) lojo keedogun osu kewaa odun yii loke eepe. Ayeye ojo ibi Oba Lamidi ni Omooba Akeem Adeyemi, eni to je okan lara awon omo ile gbimo ...
Read More »E wo ohun ti bobo yii se fun afesona re nita gbangba
Laaarin ile itaja nla kan niluu Warri, bobo yii kunle fun ololufe re. O mu oruka ife jade lapo, o si wi bayii wi pe: “Joo ololufe mi, nje o gba lati je iyawo mi?” Opolopo awon eniyan ti won ...
Read More »Awon eniyan ti bere si ni fi adura ranse si oga @DeleMomodu
@DeleMomodu, okan ninu awon oga oniroyin ile Naijeria, eni ti pupo ninu awon akegbe re feran lati maa pe ni Bob Dee, ni okan ninu oju meji re n yo lenu bayii. Won ti se ise abe fun adari ati ...
Read More »Gbenga Ojoyido n jaye bi oba Lamidi niluu Amerika
Won ti so mi lenu, idi ni yii ti mo fi pinnu lati dake. Won ti fabuku kan mi, idi ni yii ti mo fi senu mi ni deede sibi. Awon kan tile leri wi pe maa kandin ninu iyo, ...
Read More »Ile Igbimo Asofin ipinle Kwara ti kede ojo ayewo awon komisanna tuntun
Orisun Ile Igbimo Asofin ipinle Kwara ti kede ojo ayewo awon komisanna tuntun Olayemi Olatilewa Ile igbimo asofin Ipinle Kwara ti kede ogunjo osu kewaa odun yii [20/10/15]gege bi ojo ti won yoo se agbeyewo awon komisanna tuntun ti gomina ...
Read More »Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin.
Orisun Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin. Olayemi Olatilewa Awon olopaa ilu Ibadan ti bere si ni mu awon olokada ti won ba ti ko ju ero kan lo seyin ...
Read More »Awon olopaa gba owo inu saka nla mesan-an pada lowo awon adigunjale banki.
Orisun Awon olopaa fako yo! Won gba owo inu saka nla mesan-an pada lowo awon adigunjale banki. Olayemi Olatilewa Awon olopaa digboluja ti won gbogun ti iwa odaran gba obitibiti owo naira pada lowo awon adigunjale ti won dena ...
Read More »Aye akamara: Abiyamo gbe omo re ta nitori owo
Owo awon osise alaabo ti won dabo bo dukia ijoba, Nigerian Security and Civil Defense Corps, NSCDC, e ka ti ipinle Enugun ti te arabirin kan to fe ta omo bibi inu re ni egberun lona ogorun owo naira Naijiria. ...
Read More »