O Dabi Eni Wi Pe Inu Osupa Ni Maanu Yii Ti Wa
Read More »E Wa Wo Ohun Ti Omokekere Yii Da Lara: Eleyii Koja Afenu So
Lara awon iroyin wa to ti jade tele, awon iroyin lori ate Olayemi Oniroyin, mo se lalaye wi pe Edua Oke ko da ile Adulawo gege bi ibugbe awon otosi ati alaini; awon olori wa lo so ilu wa di ...
Read More »Omo Naijeria Setan Lati Dije Fun Ipo Aare Orileede Spain
Ko to di wi pe ma kan lu agbami oselu ti n gbona felifeli bayii ni ilu Spain, nibi ti Arabirin Helen Mukoro to je omo ipinle Delta lati orileede Naijeria ti setan lati dije fun ipo aare orileede Spain, ...
Read More »E Wo Ohun Ti Awon Omo Ile Igbimo Asofin Se Lodun 1962
Awon omo ile igbimo asofin Nigeria ti n foganna lojo to ti pe, ohun ti won se ni yii lodun 1962 nigba rogbodiyan Western Region. Orisun
Read More »Yomi Fash – Lanso N Jaye Oloba Niluu Côte d’Ivoire
YOMI FASH – LANSO Orisun +Wale Ojo-Lanre
Read More »Oniroyin Meji Ti Wa Ni Kirikiri Bayii: Ise Iroyin Won Lo Ko Ba Won
Alase banki Fidelity ti Nigeria, Ogbeni Nnamdi Okonkwo ni Oniroyin Seun Oloketuyi gbe saye lori ikanni re, www.naijahottestgist.com wi pe oga banki naa feran ko maa se “yodiyodi” fun awon osisebirin banki re. O ni yato si awon osisebirin re, ...
Read More »Osise Arik Airline Ba Naija Loju Je Niluu London: Won Ka “Lafun Funfun Alata’ Mo o Lowo
Owo ti te CHIKA EGWU UDENSI, okan ninu awon osise ile ise oko ofurufu ARIK Airline ni papako ofurufu HEATHROW ti ilu London pelu ogun oloro kokeeni. Ogun oloro ti won ka mo bobo naa lowo ni won ni iye ...
Read More »“Oserekurin Ti Mo Fe Lati Je Ete Re Ni…”: Tani Okunrin Ti Bimbo Thomas Feran Lati Kiisi?
Ti a ba n so nipa ise tiata ile Naijeria, Bimbo Thomas ti kuro ni ojewewe ti won nawo juwe re. Lara awon fiimu to ti kopa ribiribi ni eleyii ti Funke Akindele gbe jade ti won pe akole re ...
Read More »Milionu Mefa Ti Gbe Omo Naijeria Wonu Ese-Mefa: Ojukokoro Ti Pa Chukwudi!
Chukwudi, omo odun mejidinlogbon (28)ti padanu emi re leyin igba to ta kidinrin re ni milionu mefa owo naira (N6million)niluu Malaysia Chukwudi la gbo wi pe o tirafu lati ilu re, Owerri, ipinle Imo lati lo siluu Malaysia nibi to ...
Read More »Iyalenu: Foto Ohun To N Sele Ni Ibudo Awon Ti B’Haram So Di Alailara, Alaini Nnkankan Niyii
Ibudo awon eniyan ti Boko Haram So di alailara ati alainile lori latari ijamba ati ikolu Boko Haram ni yii ni Maiduguri to wa ni Ipinle Borno. E le biliifu wi pe sobiri ti won fi n re ile ni ...
Read More »