Ogbón kan mbe níkùn Asá,Ìmòràn kan mbe níkùn Àwòdì,Òkàn níkùn e, Òkàn níkùn mi,Òkàn níkùn ara wa,Diafun Òrúnmìlà,Baba ñ loree b’awon Àjé mulè nígbó Olúkórómójó,Wón ní kílódé,O ní nitori kí Ayé le gunO ní nitori kí igba le rò
Read More »Blog Page
EndSARS: Olórí ilé aṣojú-ṣòfin ní ìṣúnà 2020 gbọdọ̀ pèsè owó fún ASUU bí bẹ́ẹ́kọ̀…
EndSARS: Olórí ilé aṣojú-ṣòfin ní ìṣúnà 2020 gbọdọ̀ pèsè owó fún ASUU bí bẹ́ẹ́kọ̀… Fẹ́mi Akínṣọlá Olórí ilé asojú-sòfin nílẹ̀ wa, Fẹ́mi Gbàjàbíàmílà ti sòṛọ̀ nípa àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó se kókó tó n wáyé nílẹ̀ wa, paàpá ìwọ́de EndSARS. Gbàjàbíàmílà, ...
Read More »Jàǹdùkú pa ọlọ́pàá méjì, jó àgọ́ wọn mẹ́wàá, báńkì mẹ́ta, jí ọ̀pọ̀ owó l’Ékó -iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Jàǹdùkú pa ọlọ́pàá méjì, jó àgọ́ wọn mẹ́wàá, báńkì mẹ́ta, jí ọ̀pọ̀ owó l’Ékó -iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Fẹ́mi Akínṣọlá Àwọn àgbà bọ̀ wọ́n ní, ìjàngbọ̀n kìí dúró síbi tó bá rọ̀, bí kò ṣe ibi tó bá le koko. Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ...
Read More »Ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki, Ẹ̀ẹ̀mejì ni mo pe Ààrẹ Buhari lánàá , àmọ́ ń kò ri bá sọ̀rọ̀ – Sanwo-Olu
Ìṣẹ̀lẹ̀ Lekki, Ẹ̀ẹ̀mejì ni mo pe Ààrẹ Buhari lánàá , àmọ́ ń kò ri bá sọ̀rọ̀ – Sanwo-Olu Fẹ́mi Akínṣọlá Bí ọ̀rọ̀ ńlá kò bá tíì tán èèyàn ńlá kò ní tíì sinmi àròyé Sanwo-Olu tíí se Gómìnà wọn ní ...
Read More »#EndSARS: Obasanjọ, Ọọ̀ni sọ̀rọ̀ lórí ìwọ́de tó ń lọ lọ́wọ́
EndSARS:Obasanjọ, Ọọ̀ni sọ̀rọ̀ lórí ìwọ́de tó ń lọ lọ́wọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Àgbà tí òye yé kan kìí wà lọja, kí orí ọmọ tuntun wọ́, ìdí rèé tí àwọn àgbà kàn-aǹ-rìn méjì nílẹ̀ Yorùbá fi forí korí lórí ìwọ́de EndSARS tó ...
Read More »Buhari kí Obaseki kú oríire
Buhari kí Obaseki kú oríire Ààrẹ Muhammadu Buhari ti ránṣẹ́ kú orííre sí Godwin Obaseki lẹ́yìn tó jáwé olúborí nínú ìdìbò gómìnà tó wáye lónìí nípìnlẹ̀ Edo. Obaseki tó jẹ́ olùdíje dupò gómìnà lábẹ́ ẹgbẹ́ òṣèlú PDP ló fi ìdí ...
Read More »Ọ̀ọ̀ni lfẹ̀ wọ ilédì fún ọdún ọlọ́jọ́
Ọ̀ọ̀ni lfẹ̀ wọ ilédì fún ọdún ọlọ́jọ́ Bí a bá ń ṣọ̀rọ̀ ọ̀nà, yóó sòro púpọ̀ kí á tó yọ tí ẹsẹ̀ kúrò.Bí a bá sì ń ṣọ̀rọ̀ nípa ìṣẹ̀ṣe, òpó kan jàǹràn ni ilé Ifẹ̀ níbi tí ó ti ...
Read More »Odù, Ìwòrì bogbè cast for today’s Òsè Ifá
Looking at the Odù, Ìwòrì bogbè cast for today’s Òsè Ifá, it could be said that sometimes our detractors feel they are hurting us but they don’t know they are pushing us to wealth. Just listen to this stanza from ...
Read More »Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀
Tinubu, má dàá sí ọ̀rọ̀ ìdìbò gómìnà Edo–PDP kìlọ̀ Ṣé látàrí a á sìnlú a à sìnlú yìí náà lọ̀rọ̀ wá di fàá ká já a báyìí, tí àwọn ẹgbẹ́ òṣèlú ń jùkò ọ̀rọ̀ lu ra wọn.Nífèsì padà sí n ...
Read More »Òṣìṣẹ́ mẹ́rin bọ́ sí gbaga ọlọ́pàá lórí ikú ọ̀gá wọn tó rì sómi
Ìgbákejì Ọ̀gá Àgbà iléeṣẹ́ tó ń rí sí ọ̀rọ̀ owó orí, Price Water Coopers , PwC Nigeria , Tola Ogundipẹ ti jáde láyé. Ọjọ́ Sátidé ni wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ sí ní wá arákùnrin náà lẹ́yìn tó wọ ọkọ̀ ojú omi ...
Read More »