Èyí ni àwòrán mẹ́rin nínú àwọn tó wà nídìí ṣogúndogójì CBEX. Àjọ EFCC ti ń wá wọn
Read More »Blog Page
Èyí wuyì àbí kò wuyì?
Ẹ jẹ́ kí á ṣe Kábíyèsí fún Aláàfin Ọ̀wọ́adé, kí Èdùmàrè ó fi ìgbà wọn tu ìlú lára
Read More »Ǹjẹ́ ó yẹ kí ó rí bẹ́ẹ̀?
Ṣé ó tọ́ kí Ojúlówó ọmọ Yorùbá ó torí pé òun di ipò Òṣèlú mú ó máa nawọ́ láti gbọwọ́ pẹ̀lú Ọba Aládé ní gbàgede?
Read More »Ìkéde ní Yàjóyàjó láti Ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà
Ní ìtẹ̀síwájú orò ìwúyè Ọwá Obòkun Àdìmúlà ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà, Ọwá Clement Adésuyì Haastrup, wọ́n ti kéde ìṣéde jákèjádò ìlú Iléṣà. Gẹ́gẹ́ bí Olóyè Àgbà Ọlálékan Fọ́lọ́runṣọ́ tí wọ́n jẹ́ Loro ilẹ̀ Ìjẹ̀ṣà ṣe kéde, ìṣéde náà yóò bẹ̀rẹ̀ ní aago ...
Read More »Ẹ kú ojúmọ́ Ọjọ́bọ̀ tòní o!
Àwòrán Ogbè Ìwẹ̀yìn wa tòní rè, ẹ jẹ́ kí á rántí àwọn Olùkọ́ tí wọ́n máa ń kó pankẹ́rẹ́ bí ẹni tí ń tẹ̀lé Eégún. Kí lorúkọ Olùkọ́ yín tó máa ń gbé pankẹ́rẹ́ kiri nílé ẹ̀kọ́ Ṣẹ́kọ́ńdírì tí ẹ ...
Read More »Ó Pọ́dún Mẹ́ta Lónìí Tí Aláàfin Adéyẹmí Re Barà.
Kò sẹ́ni tí ó ju sáyé, gbogbo wa la ó dìtàn. Aláàfin Àtàndá ti kópa ti wọn, wọ́n ti lọ. Ọdún kẹta rèé tí Aláàfin Ọláyíwọlá ọmọ Adéyẹmí yíjú kúrò níhìn-ín, Ọláyíwọlá kọjú sáwọn aláṣekù, Baba bá wọn lọ. Iṣẹ́ ...
Read More »Ẹ̀yin ojúlówó ọmọ Yorùbá àtàtà dà?
Ǹjẹ́ ẹ mọ orúkọ tí Yorùbá ń pe ohun ti Bàbá yìí ń fọn?
Read More »Bàbá Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn
Ẹ jẹ́ kí á jọ kí GBajúmọ̀ Akọrin Jùjú nílẹ̀ yìí, Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn ti ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin (83) tó kò lónìí. Kí Olódùmarè ó fi àlàáfíà ṣe ẹ̀bùn Ogbó fún Bàbá
Read More »Mo setán láti kú’ – Tems
Mo setán láti kú’ – Tems Mary Fágbohùn Olorin Naijiria olugbafe eye Grammy, Temilade Openiyi, ti a mo si Tems, ti safihan pe oun setan lati doju ko saare nigba ti oun fi eya orin takasufe ti gbogbo eniyan mo ...
Read More »Bí Ẹ Bá Rí Ilá L’ọ́jà Kí Ẹ Ma Rà Fún Mi
Mo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹBí ẹ bá rí ikàn l’ọ́jà kí ẹ ma rà fún miMo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹAtẹ̀gbẹ̀ tí o bá délé Olódùmarè kí o ra ọmọ wẹrẹ wá fún ...
Read More »
Àṣà Oòduà Àṣà Oòduà










