A ku imura! Awo Alaseye! Isese o, o ti d’ogererere! Awo aseye l’eyin Baba wa o maa se! Aase! K – Awodiran Agboola IyaOgbe OmoEdu Yeyelufe Oyewole
Read More »Orisa Alaase, Igbakeji Olodumare
Odu Ifa Owonrin Alakara/ Ika
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a sin tu ku isimi alayo loni eledumare yio funwa ni isimi to peye ...
Read More »Oruko kan fu foto yi ?
Oruko kan fu awon arakurin yii ?
Read More »Aja To Rele Ekun To Bo..
Aja ti o ba rele ekun ti o si pada lai f’arapa ti iru aja be o si le gbegba ope olowo aja be ni yoo fi se ounje ajesun laipe ojo. KABIYESI ILU MOYE ni a o ba maa ...
Read More »Oriki Ibeji
Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, ...
Read More »Odu Ifa Owonrinwofun/ Ofun
| | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin ku isimi opin ose emin wa yio se pupo re laye o ase. Odu ifa ...
Read More »#CelebratingOsun
Ladekoju Oore Yeye Osun o! E ku odun o! Osun Sengese Oyeyenimo a gbe wa o! Aase! Photo Cc – Bekky Amusa
Read More »Odu Ifa Owonrin Tutu/ Oturupon
| | | | | | | | | | | | | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio gbo adura wa o yio si bawa tu ile aye to ...
Read More »“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo….
“Wun ó l’ówó l’ówó n tó máalo Wun ó bí’mo lé’mo n tó máalo Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo Bí Wón n n’íre lórun èmi ò mò Wun ó n’íre gbogbo n tó máalo I will have enough ...
Read More »