Home / Àṣà Oòduà (page 97)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Egbo talo daran egbaafa ninu awon mejeji ?

Alabahun (ijapa) lo re ile ana re oni ohun le so epa mefa di egbaafa ki odun to yipo, alabahun gbin epa tan ikun de’be o wu epa je ni ijapa ba ni ikun ti daran egbaafa. Ibeere talo daran ...

Read More »

Ogulutu Oro Toni – 09.08.2016

Hummmmmm onilari koseda tomola ‪#‎woo_orewa‬ Bo ba ndara fun o loni mase fi omolakeji re se yeye Mofe koranti pe kise agbara re ni ipo towa loni ‪#‎gbomi_dada‬ Iyanju lagbe ngba obami oke lo nmusu(yam) ta, bi agbara ba nbe ...

Read More »

Odu Ifa Owonrin Okanran

| |  | | | |  | | | |   | |     | Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o a sin tu ku imura toni, aku isimi opin ose emin wa yio se ...

Read More »

Òró gangan la nba Òsùn.

Read More »

A ku Ose Sango!

Owonrin Odi I II II II II I I I Owonrin sindin sapere Adifafun Bata abufun Sango nijo won torun bowaye ebo won ni kiwon ose awon mejeji gbebo won sisebo Bata ni owonrin sindin sapere Sango ani okuu temi ...

Read More »

Happy Isese Day (August 20th) in advance!

Iba Olodumare Iba Ifa Olokun Asorodayo Iba Obatala Oseeremagbo Iba gbogbo Irunmole Isese Day yio ba wa layo! Aase! Happy Isese Day (August 20th) in advance!

Read More »

Odu Ifa Owonrinsindin/edi

| | | | | | | | | | | |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, eledumare yio pin ere kanwa o, ayo ojo oni koni fiwa sile o ase. Odu ifa OWONRINSINDIN/EDI ...

Read More »

Odu Ifa Owonrin Obara – Faniyi David Osagbami

| | | | | | | | | | | | |   Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, a si ku isimi opin ose, mo gbaladura laaro yi wipe ako ni pejopo sunkun ara ...

Read More »

Ori Eni Lawure Eni O – Iyalorisa Omitonade Ifawemimo

Ori Eni Lawure Eni O Ori Eni Lawure Eni Mo ji lowuro mo dewo mori O Ori Eni Lawure Eni… Ki Ori wa ma sowa nu ooo… Ase Ire O! Translation One’s Spiritual/Inner head is his/her super spell(2ce) I woke ...

Read More »

Owe ati Ibeere Toni – 05.08.2016

– Dabimoseda Alaisan toni ohun o je eyin(egg) ejo(snake) Ibeere Toni -nje IFE otito siwa bi tati jo mo bi?

Read More »