Gomina ipinle Kogi,Ogbeni Yahaya Bollo lo n forere lori ero ayelujara pe ki won se fi orokoro ko oun lorun, oun lo ni arun covid-19 gege bi awon oloselu Kan se n gbee kiri. O ni loooto ni adari aabo ...
Read More »Ilé-ìwé Chrisland s̩e ìrànló̩wó̩ fún àwo̩n tó kù díè̩ fún l’Ekoo
Aiba won si nibe ni aiba won da sii. Eyi lo mu ki Alaga ile-iwe ati oludari, Mama Winfrey Awoshika ati Ibironke Adeyemi pese iresi, ewa, gaari ati ororo repete fun awon ti o ku die fun ni awujo.
Read More »Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ Oyo
Àkó̩kó̩ Technical University Ibadan pèsè aso̩ ìbomú àrà ò̩tun fún ìpínlè̩ OyoÌròyìn láti o̩wo̩ Yínká Àlàbí Akoko Technical University to fi ikale si ilu Ibadan se bebe ni irole ana. Won pese aso ibomu ara otun fun ijoba ipinle Oyo. ...
Read More »Ìjìyà ‘Frog Jump’ ni ọlọpàá India fi jẹ àwọn tí kò bọwọ fún òfin kónílé-o-gbélé
Ìjìyà ‘Frog Jump’ ni ọlọpàá India fi jẹ àwọn tí kò bọwọ fún òfin kónílé-o-gbélé Fẹ́mi Akínṣọlá Oríṣìríṣi ìjìyà ni ìjọba orílẹ̀-èdè India ti gbà nípaṣẹ̀ àwọn agbófinró láti máa jẹ àwọn kọ̀lọ̀rànsí tí kò bọ̀wọ̀ fún òfin kónílé-ó-gbélé ní ...
Read More »Àdúrà làsìkò yí gbà pẹ̀lú ìfaradà láti ṣẹ́gun àrùn apinni léèmí Coronavirus–Ààrẹ Buhari
Ààrẹ Buhari kí àwọn ọmọ Nàìjíríà kú àfaradà bí gbogbo nǹkan ṣe ń lọ lásìkò Coronavirus yìí Nínú ọ̀rọ̀ ìkínni kú ọdún Àjíǹde tó fi ṣọwọ́ sáwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Ààrẹ Buhari ṣàlàyé pé ìgbáyégbádùn àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kìí ...
Read More »Àwọn dókítà ilẹ̀ China tó wá sí Nàìjíríà kò ní tọ́jú aláìsàn kankan’
Àwọn Dókítà láti ilẹ̀ China tó ṣẹ̀sẹ̀ dé sí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà nítorí àjàkálẹ̀ àrùn Coronavirus kò ní tọ́jú aláìsàn kankan. Iléeṣẹ́ láti ilẹ̀ China to tó ṣe ojú ọ̀nà àti ojú irin( CCECC Nigeria), ló fi àtẹjáde náà léde pé ...
Read More »Ẹlẹ́wọ̀n 2600 ni ìjọba tú sílẹ̀ ní Nàìjíríà nítorí àrùn apinni léèmí Coronavirus
Ìjọba orílẹ̀-èdè Nàìjíríà ti tú ẹlẹ́wọ́n tó lé ní ẹgbẹ̀rún méjì sílẹ̀ ní ọgbà ẹ̀wọ̀n káàkiri orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Aregbesọla ní Ìjọba gbé ìgbésẹ̀ náà láti dẹ́kun ìtànkálẹ̀ àrùn Coronavirus ní Nàìjíríà. Mínísítà fún ọ̀rọ̀ abẹ́lé lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà náà ni àwọn ...
Read More »Òòlù ìdájọ́ ré bá Fúnkẹ́ Akíndélé àti ọkọ rẹ̀ lẹ́yìn, owó ìtánràn, ìgbélé tipátipá, iṣẹ́ ìsìnlú bíi bọ̀kílẹ̀ àfojúdi .
Kò sí n tó burú kí abẹ òfin ba Ògbó Awo tó bá ń se bí ọ̀gbẹ̀rì .Ilé ẹjọ́ ti dá gbajúgbajà òṣèré sinimá, Fúnkẹ́ Akíndélé àti ọkọ rẹ̀ Abdulrasheed Bello lẹ́jọ́ pé ó jẹ̀bi ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn ...
Read More »Àwa kò tíì gba owó ló̩wó̩ e̩niké̩ni – Boss Mustapha
Àwa kò tíì gba owó ló̩wó̩ e̩niké̩ni – Boss Mustapha Ìròyìn láti o̩wó̩ Yìnká Àlàbí Awon igbimo ti ijoba apapo gbe kale lori arun coronavirus ni awon eniyan ti n fi esun inakuna owo kan kaakiri.Eyi lo mu ki olori ...
Read More »Ewi Toni: Egbe APC iba oooo
Egbe ofo Toko coronal wo Nigeria Egbe abamo ti ki tele ofin. Akuse egbe tin pin rice agolo Kan fun eniyan mewa
Read More »