Home / Iroyin Pajawiri (page 48)

Iroyin Pajawiri

ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé òsèlú APC ni won ti kí Ààre orílè èdè yí tí a mò sí Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi.

Ogún-l’ógbòn àwon omo léyìn egbé APC ni ó ti kí Ààre Buhari káàbò sí ìpínlè Bauchi. Bauchi tí ó jé òkan Lára àwon gbòógì tí ó máa n gba àlejò Buhari láti ìgbà tí ó ti di Ààre .

Read More »

Davido ti pín àwòrán tàtúù míràn tí ó yà.

Láìpé yí ni Davido pín sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram láti pín àwòrán àti ìtàn ti tàtúù tí ó sèsè yà sí apá tí ó pè ní “30BG” kí ó tó di wípé ó fé se ...

Read More »

Cee-c pèlú Toolz àti Yaw.

Ará ilé télè ti BBnaija tí a mò sí Cee-c ti ya àwòrán pèlú Yaw ti Wazobia FM àti Toolz ti Beat FM lénìí nígbà tí won se àbèwò sí won.

Read More »

Omobìnrin tí won ti ń wá láti ojó mélòó séyìn, èyí tí ó fi ilé-èkó sílè láti tèlé Òdókùnrin kan ní ìpínlè Delta.

Àwon ebí akékòó bìnrin kékeré tí ó sonù láti bí ojó mélòó séyìn ni a ti gbó wípé arákùnrin kan ni ó wá gbe ní ilé-èkó léyìn isé òòjó náà . Omobìnrin tí ó jé akékòó ní ilé-èkó Okpe grammar ...

Read More »

Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto .

Ilé-ìwòsàn àwon ará Sokoto . Ìyá yí pọ̀ Ó ju omi òkun lọ Èdùmàrè Ìwọ tó o dá Ráábí aláṣọ Dákun má gbàgbé Ráábí eléwé Èdùmàrè ṣàánú mi Iná tó ń jó tálákà ní Nàìjíríà Ó dájú pé ó ju ...

Read More »

Omo ìbàdàn

Omo ìbàdàn Ìbàdàn mèsi ògò, n’ílé olúyòlé. Ìlú ògúnmólá, olódò kèri l’ójú ogun. Ìlú ìbíkúnlé alágbàlá jáyà-jáyà. Ìlú Àjàyí , ò gbórí Efòn se fílafìla. Ìlú Látóòsà, Ààre-ònà kakanfò. Ìbàdàn Omo ajòro sùn. Omo a je ìgbín yó, fi ìkarahun ...

Read More »

A difa fun Òrúnmìlà lojo ti baba nlo sotu ife…

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku isinmi opin ose o, bi a se njade lo loni ako ni subu lase Eledumare Àse. Laaro yi mofe fi kayefi kan to sele ni bi ojó mesan seyin ladugbo mi nilu ikorodu ...

Read More »

Owe Toni: Lati owo Jude Chukwuka

Read More »

Oríkì ìbejì

Oriki Ibeji: Wíníwíní lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ẹ̀, Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún, Ẹdúnjobí, ọmọ a gbórí igi rétẹréte, Ọkàn ń bá bí méjì ló wọlé tọ míwá, Ọ́bẹ́kíṣì bẹ́kéṣé, Ó bé sílé alákìísa, Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí ...

Read More »

Owe Toni: Lati Owo Jude Chukwuka

Read More »