Òdóbìnrin àtúnbí tí ó jé omo orílè èdè Nàíjíríà, ti jó owó rè pèlú irin gbígbóná ní èróngbà láti pa tàtúù owó rè, gégé bí ó se so wípé èsè ni , ó sì le dínà láti wo ...
Read More »Àwòrán tí ó yanilénu tí Empress.
Njamah òsèré Nàíjíríà, Empress Njamah tí ó kò láti ní adé orí , látàrí wípé ó ní owó lówó gbe lo sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà ti ara rè. Òsèré yí dàbí eni tí inú ...
Read More »Fayose se ayeye odún ketàdínlógóta (57)ojó ìbí rè pèlú ìsìn ìdúpé ní sóòsì pèlú ìyàwó rè.
Gómìnà ìpínlè Ekiti Fayose se ìsìn ìdúpé ní gbàgede Lady Jibowu ti ilé ìjoba fún ti ayeye odún ketàdínlógóta ojó ìbí rè. Àwòrán ibi tí ó ti n dì mó ìyàwó rè.
Read More »Òbísúárì okùnrin kan, ìyàwó rè pèlú omokùnrin won tí a gbó wípé won sin won ní ojó kan náà .
Oun tí ó ba ni nínújé gbáà ni ìsìnkú okùnrin kan pèlú ìyàwó rè àti omokùnrin won tí ó kú ní ojó kan náà. A gbó wípé ojó kan náà ni won ma sin wón ní ìpínlè Imo. Èyí ...
Read More »Ère Nana Akufo- Addo ni Rochas Okorocha fé sín ní Imo.
Gómìnà ìpínlè Imo, Rochas Okorocha ti se tán láti sín ère ààre Nana Addo ti Ghana ní Owerri nígbà tí ó ti sí ère ti ààre Ellen Sirleaf ti Laberia àti Zuma ti South Africa . Ère náà ti ...
Read More »Destiny Etiko wo sòkòtò bénbé pèlú aso yí ó ba mu.
Òsèré Nàíjíríà tí a mò sí Etiko Destiny ti jáde láì wo Kómú. Òsèré yí wá gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti pín àwòrán tí kò wo Kómú yí.
Read More »Gómìnà Obaseki se ayeye odún kan tí ó ti dé ipò, Akeredolu àti Amaechi náà sì ba yò.
Gómìnà ìpínlè Ondo, Akeredolu lo bá Gómìnà ìpínlè Edo se àjoyò odún kan tí ó dé ipò ní pápá Samuel Ogbemedia, Benin city.
Read More »Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Ààre Buhari ní ìpínlè Anambra fún ìpolongo Dr. Tony Nwoye fún àwon omo egbé APC.
Read More »Regina Daniel rewà ó sì dàbí àgbàlagbà níbi àwòrán tuntun tí ó sèsè yà.
Òdóbìnrin òsèré yí, Regina Daniel ti gbe lo sí orí ìtàn èro ayélujára (insta-stories) láti pín àwòrán tí ó ti yàtò yí.
Read More »Sandra Okagbue ya orúko flavour “Chinedu” sí owó rè .
Ìyá omo olórin flavour, Sandra tàtúù orúko rè “Chinedu” sí apá .
Read More »