Àwòrán àwon tokotaya tuntun, kí olórun fún won ní adùn ìgbéyàwó . Èyí ò wa rewà bí…
Read More »Patoranking lo kí Timaya pèlú okò rè tuntun tí won n pè ní Porsche.
Gégé bí Timaya se pin sí orí èro ayélujára(Instagram) tí ó sì wípé . ” omo mi ti dé pèlú àrà òtò, gbogbo ìgbà ni ó ma n mú orí mi wú. PATORANKING mo féràn re ….
Read More »Ìlò wèrè aso Okrika (aso tí won ti lò rí).
‘Okrika’ ni ònà tí àwon ènìyàn Nàjíríà n gbà pe aso tí won ti wò rí, tí won sí wo ìlú. Nígbà tí àwon nkan ti sa èyí tí ó dára níbè àwon kan kò ní aso tí won ...
Read More »Omoni àti Nnamdi Oboli se ayeye ìrántí odún métàdínlógún (17) ìgbéyàwó won pèlú àwòrán tí ó ti pé.
Gbajúgbajà òsèré, Omoni Oboli àti oko rè Nnamdi se ayeye odún métàdínlógún ìgbéyàwó won. Won sì pín àwòrán tipétipé won…
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbéyàwó tí tokotayà yí yà.
Gift Clarke, èyí tí a gbó wípé ó fé fé àfésónà rè kí odún yí tó parí, ni ó pín àwòrán kí won tó se ìgbéyàwó tí ó rewà yí. Oko àti aya sì dàbí egbin…
Read More »Ay Makun àti Aliko Dangote níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki .
Ìgbéyàwó omo Saraki tí ó ti gbòde kan tí àwon òtòkùlú orílè-èdè Nàíjíríà sì péjú pésè níbè. Ay apanílèrín àti Aliko Dangote náà sì lo. Won sì jo ya àwòrán níbi ìgbéyàwó naa….
Read More »Tinubu, Modu Sheriff, Ben Bruce níbi ayeye ìgbéyàwó omo Saraki.
Ní ìsàlé ni àwòrán ayeye ìgbéyàwó omo Saraki tí ó n jé Olutosin Halima Saraki, omobìnrin Saraki, omo asojú ilé-ìgbìmò asòfin , Bukola Saraki tí won se ní ilé ìtura àti ìgbàlejò (Eko hotel and suites ) ìpínlé…
Read More »Omokùnrin Amanda Ebeye se ayeye odún kan ojó ìbí rè.
Ìyá tí inú rè n dùn pín àwòrán òun àti omokúnrin rè sí orí èro ayélujára (Instagram) tí ó sì ko síbè wípé ” kú ayeye ojó ìbí rè omo Mi…..Ayé mi ….Enìkejì mi…. Eni tí ó ...
Read More »Kí le ma se fun tí ó bá jé omo yín lásìkò yí.
Èmi ma le àpótí mo…
Read More »Àwòrán Mompha àti àwon omobìnrin Chinese tí Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá won sùn.
Síwájú Hushpuppi bú òré rè tí ó so wípé kò ní owó lówó lórí èro ayélujára (Instagram). Hushpuppi fi èsùn kàn án wípé ó n bá àwon omobìnrin Chinese tí kò to sùn. Àwòrán Mompha re, pèlú àwon ...
Read More »