Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose ...
Read More »Ipade! Ipade! Ipade!
“Mo se ileri fun orisun mi Ti I se ile yoruba, Lati je omo yoruba atata nileloko, Ati lati je omo oko, Ti ki I f’owo osi Juwe ile baba re, Lati gbe ise, asa Ati ede yoruba laruge, Nibi ...
Read More »Pari owe yii..
Bi ọdẹ ba ro iṣẹ, ro iya, boba pẹran ………..
Read More »Ogulutu Oro Toni – 11.09.2016
Hummmmmm ile eni lati nje ekute oni dodo, Morojo oko re feni kankan mo Tori Kosi bi tise o si oni kaluku naa nfaso bo tie ni wara o si loni, wara nbo lola Woo Orewa Kosokunrin tope nile aiye ...
Read More »Yoruba Bo Won Ni Agbomojo Lomo N Moju…
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Ido Alayo ti ose yi. ...
Read More »Idile Alayo Toni – 17.09.2016 (E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo)
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wi pe a ku aseku odun emi wa yoo se pupo re laye, layo ati ni alafia ara. Mo si ki awa ololufe eto yi, wi pe e ku ...
Read More »Iyawo re o, a mo eni towu oooo!
Owo idana o po ooo 5,000 pere ni oooooo
Read More »N je e ran’ti iwe yii?
Eyelé kìí léegun ìsé lára …
Eyelé kìí rìnrìn ìyà l’ésè Eye tó bá ye làá pè l’éyelé. Good morning Universe!!! May the blessing of today abide with each and everyone of us. Ase!!! Popoola Owomide Ifagbenusola
Read More »Olojo Ibi Toni – Arabinrin Adetona Banke
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Arabinrin Adetona Banke ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...
Read More »