Home / Tag Archives: Àṣà Yorùbá (page 66)

Tag Archives: Àṣà Yorùbá

Eeto Owe L’esin Oro 4

Mo ki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa owe l’esin oro. Laakoko, mo dupe lowo Olodumare ti o funwa ni oore-ofe lati tun pade loni, leyin igba ti a dagbere fun eeto ni ose to koja. Moki kabiyesi ...

Read More »

Olojo Ibi Toni

Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Alagba Oluwakayode Olamilekan Adekoya Ijeni ti won je okan gboogi ninu ebi Omo Yoruba. Okan pataki ni won je lara awon majekobaje ilu yi, oloye nla niwon laafin Olumoye. ...

Read More »

Ibeere Toni: laiye ‪#‎Ijohun ati ‪#‎Aye Ode oni

Ojuwo lefi wo asa ila kiko laiye ‪#‎IJOHUN‬ ati ‪#‎AIYE_ISIN‬ …..nje odara kamo ko omo wa nila bi???

Read More »

Yoruba Du ‘n ka

Yoruba dun-un ka yoruba e komo yin o, ko tun le ko ko tun le so ede abinibi. A~ AJA, B~ BATA, D~ DOJE, E~ EJO, E~EYE, F~ FILA, G~ GELE………. A B D E E F G GB H ...

Read More »

Foto: Ara Kenge !

E bami kira fun Ife….gbosa, gbosa, gbosa  

Read More »

Orin, Owe ati Ewi !

ORIN : ” Ododo-Eye mi, ko ma re danu .. Ko maa re danu, Loju aye mi.. Ile nimo ko o, Oko nimo ra.. Omo,Omo l’adele o… …… OWE : * Agba waa bura bewe o ba se-o ri. * ...

Read More »

Idile Alayo: E Gbo Bi Atejise Na Ti Lo

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...

Read More »

Ounje UNJE Eme Fun T’ooro Yii – 26.05.2016

HUN ! B’o ti wu ki a pe laye to … A pee lorun ju bee lo… :::: WOO ORE WA ! ‪#‎Igba‬ o lo bi ‪#‎Orere‬.. Bee, ‪#‎Laye‬ taa wa yii ko lo bi ‪#‎Opa_ibon‬ ::::::: DAKUN ORE WA ...

Read More »

Odo Iwoyi – 2

Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...

Read More »

Eeto Owe L’esin Oro – 3

A ku deede asiko yii o ni aafin ilumoye, moki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa OWE L’ESIN ORO, oro l’esin owe ti oro ba sonu owe ni a o fi waa jade. Ope nla lo si ...

Read More »