Olayemi Olatilewa Omokunrin eni odun merindinlogun (16) kan ti lo foju ba ile ejo niluu Abuja leyin asemase pelu omobirin, eni odun meji (2) kan. Iroyin yii lo jade nigba ti olupejo, ogbeni Adama Musa, eni ti n soju ile ...
Read More »Owo te awon omo egbe okunkun niluu Ado-Ekiti
Olayemi Olatilewa Awon akekoo meji ile iwe gbogbonise ti ijoba apapo (Federal Polytechnic) to kale si Ado-Ekiti ati maanu kan ti n tu foonu se ni agbegbe naa ni won ti ko lo si iwaju ile ejo Majisireeti pelu esun ...
Read More »Ireti Odegbami ja sofo lati di aare FIFA agbaye
OlayemiOlatilewa Bi o tile je wi pe ajo ere boolu ile Naijiria ti n fenu so wi pe gbagbaagba ni awon wa leyin agbaboolu to gba boolu metalelogun (23) sawon ni akoko ti n gba boolu fun orileede Naijiria, ...
Read More »“Bilionu lona bilionu owo naira ni Mimiko dabaru ni ipinle Ondo” – Alagba egbe APC
Olayemi Olatilewa Alaga egbe oselu APC eka ti ipinle Ondo, ogbeni Isaac Kekemeke ti fesun kan Gomina Olusegun Mimiko to je omo egbe oselu PDP nipa wi pe owo bi tirilionu kan naira (N1 trillion) ni gomina ti je mole ...
Read More »Ooni tuntun wo ilu Ile-Ife tilu-tifon
Omooba Adeyeye Enitan Ogunwusi ti wo ilu Ile-Ife fun imurasile fun iwuye re ti o waye ni kopekope yii
Read More »E wa wo ise opolo to fakiki
Ise awon asaraloge ni ki won tunrase. Sugbon nigba mi-in, won tun le baraje. Sebi bise ba se gba ni won se n se e. Ise opolo ni ise tiata, awon onitiata ni won se ise opolo. Foto: eni ti ...
Read More »Yanju Adegboyega: Ohun ti won wi ti ko koreeti”
“Nje e mo pe “oye to kan ara Iwo, o n bo wa kan ara Ede, tawon kan maa n wi yen ko koreeti? Ilu kan n be ni ka to de Ede ti won n pe “Awo”, ilu yii ...
Read More »Ile ejo ti ran Jimoh lewon leyin to fi ehin ja ori oyan asewo niluu Ibadan
Ile ejo ti ran Jimoh lewon leyin to fi ehin ja ori oyan asewo niluu Ibadan Orisun Oniroyin: Twitter Ile ejo Majisireeti ti n jokoo niluu Ibadan ti ran Ogbeni Sunday Jimoh lewon bayii leyin igba to fi ehin ja ...
Read More »Won je David Mark, Amaechi ati Fasola lenu bi obi abata
Orisun Oniroyin Twitter Won je David Mark, Amaechi ati Fasola lenu bi obi abata *Didake David Mark n ko awon eniyan lominu *Asa tuntun ti won da: “Mi o gba riba ri laye mi” – Amaechi “Gege bi gomina, mi ...
Read More »Ewi Awon Omode: E Ma Ya Baseje
Ewi: E ma ya baseje Eyin ewe iwoyii, e wa teti si agogo ogbon E ma ya baseje Baseje ti n bale je ni won pe larungun Arungun ni eni ti n ba ohun ti won fowo se je ...
Read More »