Kayode Odumosu,papòdà lẹ́ni ọdún mẹ́tàdínláàdọ́rin Gbajúgbajà òṣèré tíátà Kayode Odumosu tí gbogbo èèyàn mọ̀ sí Pa Kasumu ti juwọ́ ìgbẹyìn sáyé pé ó dìgbàkan. ”Èèyàn dáadáa ni wọ́n yàtọ̀ sí pé wọ́n jẹ́ òṣèré tíátà.Ikú wọ́n jẹ́ eléyìí tó fi ...
Read More »Ìjàm̀bá iná se ò̩nà Eko sí Ibadan ati Ibadan sí Eko pa
Ìjàm̀bá iná se ò̩nà Eko sí Ibadan ati Ibadan sí Eko paÌròyìn láti o̩wó̩ Yínká ÀlàbíOro gbogbo kii se lori alabahun ni opopona Eko si Ibadan ati Ibadan si Eko. Lati igba ti awon Julius Berger ti bere ona naa ...
Read More »Akiyesi Pataki
Arákùnrin oníṣègùn oyinbo tó jẹ́ ọmọ bíbí Nigeria to wá n’ilu USA, fi ọrọ ìyànjú yí ranṣẹ fún anfaani ara wa. Jọ̀wọ́ ká, kí ó sì mú lo fún ìtọ́jú ara rẹ. Dr. A. Malgwi Ọna ti àwọn ọdọ wá ...
Read More »Nnkan méje ti yóò yipada àti meje ti kò ni yi pada lẹ́yìn ti ilẹ Gẹ̀ẹ́si ti kuro labẹ EU
Lẹ́yin ọdún mẹ́ta lílọ bibọ̀ lórí ọ̀rọ̀ Brexit, ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́ṣì padà kúrò lábẹ́ EU ní aago mọ́kànlá alẹ́ ọjọ́ Jimọ ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n Oṣù kínní ọdún 2020.
Read More »Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojú
Kí gbogbo àwọn olórí ààbò lọọ rọ́kún nílé – Ilé ìgbìmọ̀ asojúLáti ọwọ́ Yínká Àlàbí Abajade ipade ile igbimo asoju to wa ni Abuja ni “a kuku joye san ju enu mi ko ka ilu lo”. Won ni ki gbogbo ...
Read More »Jonathan sàbẹ̀wò sí Buhari
Ara iroyin yajoyajo to wole ni abewo ti Aare ana, Omowe Goodluck Jonathan se si Aare Mohammadu Buhari ni Aso Villa to wa ni oluulu Naijiria ni Abuja. Ipade bonkele ni ipade yii nitori pe awon mejeeji tilekun mori ni, ...
Read More »Ìjọba Àpapọ̀ Kò Gbẹ́sẹ̀lẹ̀ Lé Owó Tó Tọ́ Sáwọn Ìjọba Ìbílẹ̀ L‘ọyọ
Lórí ọ̀rọ̀ kan tó gbà gboro kan pé àgbẹjọrò àgbà orilẹ̀-èdè Naijiria, Abubakar Malami ti pàṣẹ fún gómìnà ìpínlẹ̀ Oyo láti gba àwọn alága káńṣù ti wọ́n yọ nípò pada, Ìjọba Ọyọ ti fèsì lórí ìṣẹ̀lẹ̀ náà.
Read More »Ó ju ẹnu Malami lọ láti ní ètò náà kò bófin mu
Kí ojú má ríbi, gbogbo ara lòògùn rẹ̀, èyí ló mú kí Gómìnà ipinlẹ Ọyọ, Ṣèyí Mákindé sáré tètè gba ìlú Abẹokuta lọ, láti lọ ṣèpàdé pọ̀ pẹ̀lú Olóyè Olusẹgun Ọbasanjọ.
Read More »Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá
Ẹ kéde iye ọlọ́pàá tó gba rìbá, kí ẹ tó má a yin ra a yín… Aráàlú sọ fún iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Èsì àwọn ọmọ Nàìjíríà tó tẹ̀lé bí iléèṣẹ́ ọlọ́pàá ṣe yin ara rẹ̀Lórí káàdì tí wọ́n fi síta lójú ...
Read More »È̩ ń fi ẹ̀wọ̀n run imú ẹ̀yin Olóyè Ìbàdàn mọ́kànlélógún tẹ ń ǹ pera a yín lọ́ba
Ọrọ̀ kò tíì tán lórí àwọn Olóyè mọ́kànlélógún tí Ilé ẹjọ́ sọ pé kí wọ́n lọ rọọ́kún nílé nílùú Ìbàdàn. Kọmíṣọ́nnà ètò ìdájọ́ tẹ́lẹ̀rí nípìńlẹ̀ Oyo, Ọ̀gbẹ́ni Michael Lànà ló ṣe ìkìlọ̀ fún wọn pé, kí wọ́n yé pe ara ...
Read More »