Olè yabo báńkì. O fowó náà so̩dún Kérésì fáwọn èrò Bí ayé bá ń lọ sópin, àràǹbarà ìran lojú yóó máa rí. À bí kín ní ká tí pèyí sí pẹ̀lú bí arákùnrin òyìnbó onírungbọ̀ kan ṣe dédé yabo ilé ...
Read More »Ìjà ìgboro bé̩ sìlè̩ lórí Sowore
Ogbeni Omoyele Sowore to je aja-fun-eto- omoniyan to tun je oludije du ipo Aare ni odun yi ni o ti wa ni ahamo awon agbofinro lati bii osu meta seyin.Ile-ejo ni ki o maa gba ile wa jejo sugbon ijoba ...
Read More »Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì
Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì Ọgbà ẹ̀wọ̀n ni pásítọ̀ Sòtítọbirẹ̀ yóó ti ṣe kérésì Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ondo ti gbé Pásítọ̀ Alfa Babatunde tíí ṣe olùdásílẹ̀ Ìjọ Sòtítọbírẹ ní Ondo lọ Ilé ẹjọ́ léyìí tí ìwòye sì ...
Read More »Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti Dasuki
Ìjo̩ba àpapò̩ t’ókun ló̩rùn Sowore àti DasukiLati owoYinka AlabiIjoba apapo orileede Naijiria ni o ti ni ki Ogbeni Omoyele Sowore ti o je oludari “iroyin ayelujara Sahara” ati Sambo Dasuki ti o je oluba-Aare damoran pataki (NSA) nigba isejoba Goodluck ...
Read More »Mo ti pàṣẹ fún àjọ DSS láti tẹ̀lé àṣẹ ilé ẹjọ́….Abubakar Malami
Ìjọba àpapọ̀ ti pàṣẹ pé kí wọ́n tú olùbádámọràn lóri ètò ààbò Sambo Dasuki àti agbétẹrù Revolution Now Omoyele Sowore silẹ̀ nínú àhámọ́.
Read More »Ìjọba àpapọ̀ f’ẹ́ já iná mànàmáná orílẹ̀èdè Togo àti Benin Republic nítorí gbèsè $7m
Ìjọba àpapọ̀ f’ẹ́ já iná mànàmáná orílẹ̀èdè Togo àti Benin Republic nítorí gbèsè $7m Ariwo t’íjọba àpapọ̀ Nàìjíríà ń pa lé àwọn tó jẹ ẹ́ ni gbèsè owó iná nìyí báyìí o. Ṣùgbọ́n lọ́tẹ̀ yìí kìí ṣe àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè ...
Read More »Ó di láyéláyé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè
Ó di láéláé pọngbá ! Àlàbí Yellow ,àgbà òṣèré re’bi àgbà á rè Gbajúgbajà òṣèré Samuel Akinpẹlu tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Àlàbí Yellow ti jẹ́ Ẹlẹ́dàá nípè. Akọni tí à ń perí yìí jẹ́ òṣèré tí àwọn èèyàn kò ...
Read More »Àlùfá tọ́ bá ọmọ ọdún méje sùn, wẹ̀wọ̀n ọdún Márùn- ún ní ìpínlẹ̀ Ekiti
Ọjọ́ gbogbo n t’olè, ọjọ́ kan n t’olóhun.Ìjọba ìpínlẹ̀ Ekiti tífìtàn balẹ̀ bí wọ́n ṣe jẹ́ ìpínlẹ̀ àkọ́kọ́ tí yóò bẹ̀rẹ̀ láti máa dárúkọ ọ̀daràn afipá bánilòpọ̀ hàn àti láti máa dójú tì wọ́n. Gómìnà ìpínlẹ̀ náà Kayode Fayemi gbé ...
Read More »Ìdí tí a fi yọ Donald Trump nípò Ààrẹ
Alágbára ayé,alágbára ayé,a sè a ṣẹ̀ má lù kan, Ọlọ́run o tíì da sí dúníyàn .Bí nǹkan se n lọ yìí, Donald Trump ni Ààrẹ orílẹ̀èdè Amẹ́ríkà kẹta nínú ìtàn tí ọ̀bẹ yóó bá ń dìí láti ọ̀dọ̀ àwọn Ilé ...
Read More »Kò sí ilé tàbí só̩ò̩bù tí a kò le fo̩ láti ké̩rù òfin – Àjo̩ Customs
Awon ajo asobode ile Nigeria ti gbogbo eniyan mo si Customs ni won n ba awon oniroyin soro ni ipinle Adamawa pe, ko si ile tabi soobu ti awon ko le ja tabi fo ti o ba ye.Won ni gbogbo ...
Read More »