Home / Tag Archives: iroyin (page 10)

Tag Archives: iroyin

Ayédèrú ni ‘plate number Chief Whip’ Kano – FRSC

Iroyin asise nomba moto asofin ilu Kano, Ogbeni Ayuba Durum ran kaakiri bi ina inu oye, paapaa julo lori ero ayelujara. Eyi wa ya gbogbo aye lenu pe se bee ni awon ajo FRSC tii se adari eto irinna ati ...

Read More »

Lai Mohammed fa o̩mo̩ Naijiria létí lórí ìròyìn òfegè

Lai Mohammed fa ọmọ Nàìjíríà létí lórí ìròyìn òfegè Fẹ́mi Akínṣọlá Mínísítà ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ìròyìn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Lai Mohammed ti ní ìjọba yóò bẹ̀rẹ̀ ṣí í ṣe àmójútó àtagbà ojú òpó ayélujára báyìí.Ìgbésẹ̀ yìí ni láti ṣe àfọ̀mọ́ ojú ...

Read More »

Vietnamni , ẹ wá dá oko ìrẹsì sílẹ̀ ní Nàíjíríà, dípò kíkórẹsì wọlé– Oshiomole fèsì ẹ̀bẹ̀

Vietnamni , ẹ wá dá oko ìrẹsì sílẹ̀ ní Nàíjíríà, dípò kíkórẹsì wọlé– Oshiomole fèsì ẹ̀bẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Bí Ìjọba Nàíjíríà se gbé àwọn ẹnu ọ̀nà àbáwọlé sí orílẹ̀ -èdè yìí tìpa ti ń mú kí orí ta àwọn lórílẹ̀-èdè ...

Read More »

Atiku tún pàdánu nílé e̩jó̩ tó ga jù

Atijo tun padanu nile ejo to ga juLati owoYinka AlabiIle-ejo to ga ju lo ni orileede yii ti se idajo lori ejo ti oludije dupo Aare ni abe egbe oselu PDP, Alhaji Atiku Abubakar.Ile-ejo ni Aare Muhammadu Buhari naa ni ...

Read More »

Akpabio fajúro sí owó ìnákúùná Niger Delta

Akpabio fajuro si owo inakuna Niger DeltaLati owoYinka AlabiIjoba apapo ti Senato Akpabio n soju fun lo ti gbanaje lori awon ise ajanbaku to n waye ni agbegbe Niger Delta. Akpabio ni o ye ki ise ijoba maa te siwaju ...

Read More »

Màmá àádó̩rin o̩dún ròó pin sí ófíìsì àwo̩n oníná mò̩nàmó̩ná

Màmá àádó̩rin o̩dún ròó pin sí ófíìsì àwo̩n oníná mò̩nàmó̩náLati owoYinka AlabiIya agbalagba ti ko din ni aadorin odun lo lo roo pin si ofiisi ajo apina-ka (IBEDC) Ibadan Electricity Distribution Company to fi ikale si ilu Osogbo.Mama yii di ...

Read More »

Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú mi – Aláàfin Ò̩yó̩

Ọmọọba mẹwàá ló du òyè pẹ̀lú Adeyẹmi, tó sì já mọ lọ́wọ́. Fẹ́mi Akínṣọlá Ọlayiwọla Adeyẹmi Kẹta, ti pé ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gọ́rín lókè eèpẹ̀ bẹ́ẹ́ ló ti lo ọdún méjìdínláàdọ́ta lórí ìtẹ́ àwọn baba ńlá rẹ̀. Òjò ti ń pa ...

Read More »

llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́

llé iṣẹ́ ọ̀lọ́pàá ,ẹ dá ìgbaniwọlé tí ẹ gùnlé dúró… Àṣẹ ilé ẹjọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé àwọn àgbà ní ilé tí a fi itọ́ mọ, ìrì ni yóò wo. Ọbẹ̀ tí a fi èké pilẹ̀ ẹ rẹ̀, í í ru ...

Read More »

Ṣé Ìwọ mọ pé gbogbo agboolé nílùú Igbóọrà ní wọn ń bí ìbejì ?

Ṣé Ìwọ mọ pé gbogbo agboolé nílùú Igbóọrà ní wọn ń bí ìbejì ? Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé kò sí ìlú tí kò ní àdámọ́ ọ ti ẹ̀. Bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí nílùú Igbóọrà .Igbóọrà jẹ́ ìlú kan tó kalẹ̀ si ...

Read More »

Seyi Makinde, mo gbà fún ọ lórí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ tó o ṣe ní ìpínlẹ̀ Oyo—Yemi Ọṣinbajo

Seyi Makinde, mo gbà fún ọ lórí ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ tó o ṣe ní ìpínlẹ̀ Oyo—Yemi Ọṣinbajo Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣe wọ́n ní yini yini kí ẹni le sèmí ì ,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ lọ̀rọ̀ rí,nígbà tíIgbákejì Ààrẹ ilẹ wa, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yemi Osinbajo gbósùba ...

Read More »