Obirin yii ni won ti se idajo Sharia fun ni orileede Indonesia latari wi pe, gbogbo igba lo n tele okunrin kan eleyii ti kii se oko re. Awon kan tile tun jeri wi pe, oseese ki maanu naa ti ...
Read More »Aregbesola sedaro Hon. Makinde to doloogbe
Gomina ipinle Osun, Ogbeni Rauf Aregbesola ti ranse ibanikedun si idile Hon Makinde Oladejo Samson to doloogbe lojo Aiku to koja yii, 27/12/15. Hon Makinde, omo egbe PDP, to je okan lara awon omo ile igbimo asofin ipinle Osun lo ...
Read More »IROYIN OWURO ose yii ti jade ooo
Iru iku wo lo pa Sikiru Ayinde Barry Wonder? Inu iwe Iroyin Owuro ose yii ni e o ti ri. E gbiyanju ke e bere lowo fendo yin. Ogorun naira pere ni.
Read More »IROYIN OWURO ose yii ti jade oooooooo
Ese ‘o gbero ni Ikenne Paradise ni mama wa bayi – Pst Adeboye Opelope Mama Kapenta nii nba je – Pst Bakare Okunrin to feran ibalopo pelu okunrin farahan ni Abeokuta Oju to maa ti awon ti won nbu ijoba ...
Read More »Ladoja setan lati gba ipo gomina pada lowo Ajimobi ni kootu
Ladoja ati Ajimobi: Taani ipo gomina yoo ja mo lowo ni kootu? Oniroyin: Olayemi Olatilewa Orisun Oniroyin: Twitter Nibayii, won ti kede ojo ti won yoo pari ejo, eleyii ti o je asekagba, to wa laaarin Senato Rasheed Adewolu Ladoja ...
Read More »Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe
Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe Iroyin Owuro ose yii tun ti gori igba. Iwe iroyin ti n gbona felifeli. Die ni yii ninu awon koko ...
Read More »#OGULUTU: Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata
E ku asiko yii eyin eniyan mi, ko to di wi pe n maa se alaye ara mi tabi abala Ogulutu to je tuntun to gori Iwe Iroyin Owuro. E je n sare bi yin nipa oun ti won pe ...
Read More »