È̩yin òsìsé̩ mi nílò àyè̩wò coronavirus kíákíá – Akeredolu Arakunrin Rotimi Akeredolu ti o je gomina ipinle Ondo lo n gba awon alabasise re niyanju ki won fi oro ti oun se arikogbon. O ni iba lasan ni o se ...
Read More »Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC
Àwo̩n aké̩kò̩ó̩ ti lè wo̩lé, mótò ti lè rìn làti ìpínlè̩ sí ìpínlè̩ – NCDC Ijoba apapo ti fowo si aba ti awon ajo NCDC gbe lo si odo Aare. Ijoba fi aaye sile ki awon ara ilu maa rin ...
Read More »Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn
Ògún Majek wọ káà ilẹ̀ sùn Ọlọ́jọ́ ń kajọ́, ẹ̀dá ò fiyè si.Ìjọ ọmọ tuntun dáyé, nijọ́ ìdùnnú, ẹ̀rín, òhun ọ̀yàyà fún ẹbí,ará, pẹ̀lú ìyekan. Ṣùgbọ́n kìí rọgbọ ká sàdédé sàfẹ̀kù èèyàn ẹni pékú yọwọ́ ọ rẹ̀ ní dúníyàn. Àsamọ̀ ...
Read More »Abiola Ajimobi sùn un re
Ikú pàgbẹ̀ àṣírí aláró tú.Ikú pàlùkò àbùkù kará ìkosùn.Ọrùn má kánjú, gbogbo wa la dágbádá ikú.Ìgbà átàsìkò ẹ̀dá ló só kùnkùn.Gíńgín ladáhunṣe tó mewé e re.Gbogbo wa lòpè nípa àkúnlẹ̀yàn.Òkú ń sunkú òkú, akáṣọlérí ń sunkú ara a wọn.Sùn un ...
Read More »Abọ ìwádìí yóó ṣọ pàtó ikú tó pàwọn òṣìṣẹ́ wa– Àjọ FRSC
Abọ ìwádìí yóó ṣọ pàtó ikú tó pàwọn òṣìṣẹ́ wa– Àjọ FRSC Ìlú u gángan lọ̀pọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ láyé,n Iàwọn àgbà se ṣọ pé,ẹ̀yìn ló kọ sẹ́nìkan, n tó kọjú sẹ́lòmíìn.Bí a kò bá gbàgbé, àìpẹ́ yìí ni ìṣẹ̀lẹ̀ ajániláyà pàtì ...
Read More »INEC kọ lẹ́tà APC láti ṣe ìbò abẹ́nú l‘Ondo
INEC kọ lẹ́tà APC láti ṣe ìbò abẹ́nú l‘Ondo Ṣé àwọn àgbà ní bí eégún kò bá ṣe n tó tóbi, atọ́kùn rẹ̀ kìí tú ìdí rẹ̀ wò. Àjọ olómìnira tó ń ṣe kòkárí ètò ìdíbò Orílẹ̀ yìí tí fọnmú ...
Read More »Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò
Ilé ẹjọ́ kòtẹ́mílọ́rùn yọ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC Adams Oshiomhole nípò– Ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn ti ilú Àbújá ti yẹ àga mọ́ alága ẹgbẹ́ òṣèlú APC, Adams Oshiomhole nídìí Ìgbìmọ̀ ẹlẹ́ni mẹ́tà ti adájọ́ Eunice Onyemanam sójú fún ni wọ́n fẹnu ...
Read More »Orisirisi: Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC
Àwọn àǹjàǹnú ń gbowó oṣù l’ájọ Sùbẹ́ẹ̀bù Kwara- EFCC Àjọ tó ń gbógun ti ìwà jẹgúdújẹrá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà EFCC sọ pé àṣírí àwọn ayédèrú òṣìṣẹ́ ẹgbẹ̀rún kan àjọ tó ń ṣàkóso ètò ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ nípìńlẹ̀ Kwara ti tú sí àwọn ...
Read More »Èèyàn 627 ló lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Naijiria ní Ọjọ́ Ẹtì
Èèyàn 627 ló lùgbàdì àrùn Coronavirus ní Naijiria ní Ọjọ́ Ẹtì Ẹgbẹ̀ta lé lọ́gbọ̀n o dín mẹta èèyàn (627 )tuntun míì ló ṣẹ̀sẹ̀ lùgbàdi àrùn Kofi -19 ní Nàìjíríà. Àjọ tó ń rí sí ìdènà àti amójútó àjàkálẹ̀ àrùn apinni ...
Read More »Olu Jacobs sì wà láàyè
Olu Jacobs sì wà láàyè Agba oje ninu ere ori itage ni ede Oyinbo, Alagba Olu Jacobs ni awon iroyin eleje kan n gbee kiri lori ero ayelujara lati aaro oni pe, “olodi baba naa ti lo je ipe awon ...
Read More »