Orewa kilode kilo fa ironu?
Bao ku ise o tan toripe yoruba bo won ni airise koni kapada si orun-alakeji tiko basi oko (farm) ao si ma re idale(travel) ko si eni to la laye yi tiko ni ri nkan wi, amo saa ti oro ...
Read More »
Bao ku ise o tan toripe yoruba bo won ni airise koni kapada si orun-alakeji tiko basi oko (farm) ao si ma re idale(travel) ko si eni to la laye yi tiko ni ri nkan wi, amo saa ti oro ...
Read More »Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe ...
Read More »Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun ...
Read More »Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. ...
Read More »E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu December -Ope.
Read More »A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E ...
Read More »Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi mama wa TUNRAYO IBRAHIM ti won je okan pataki ninu ebi Oodua Rere. Iyalode olojo ibi a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re laye ...
Read More »Ebeere Toni: Talo ma pani lerin julo ninu awon won yi?
Read More »