Omoge kan ni owó tè tí won sì fi se èsín látárí wípé ó fo odi ilé onílé láti jí bisikitì .
Ònlò èro ayélujárá ( Facebook) tí a mò sí Arc Pashal Chike Umeobi ló so wípé arábìnrin yí ni owó àwon figilanté tè ní Ezinifite , ìlú kan ní ìpínlè Anambra . Arábìnrin yí ni won fi ...
Read More »