Home / Àṣà Oòduà / Atiku, Saraki, Dogara ati Melaye lè má bó̩ nínú e̩jó̩ jìbìtì Hushpuppi- APC

Atiku, Saraki, Dogara ati Melaye lè má bó̩ nínú e̩jó̩ jìbìtì Hushpuppi- APC

Atiku, Saraki, Dogara ati Melaye lè má bó̩ nínú e̩jó̩ jìbìtì Hushpuppi- APC

Ogbeni Ramoni Igbalode Abbas to je omo Naijiria ti owo te ni ilu Dubai pelu esun jibiti lilu lori ero ayelujara lose to koja ni egbe oselu APC ni owo PDP ko mo nibe.


Gege bi atejade to egbe oselu APC gbe jade nipa irinkurin egbe oselu PDP paapaa julo ni asiko idibo odun 2019 to koja. APC ni ki won to so pere, won ti ko ara won lo Dubai fun ipade.


APC ni iru ipade wo ni won n lo se ni orileede naa ti ko see se ni Naijiria. APC tun ni gbogbo foto ti won ya pelu Hushpuppi nibi ipade ati gbogbo ohun to da won po lo maa jade laipe.

APC ni o da awon.loju to ada pe awon oyinbo maa wadii gbogbo irinajo Ogbeni afunrasi naa.

Gege bi atejade egbe APC ti igbakeji akole agba egbe naaogbeni Yekini Nabena fowl si, APC ni ki egbe PDP maa se sun asunpiye nitori ejo naa ti kuro ni Dubai lo si Chicago ni orileede Amerika. O ni afaimo ki Ogbeni Hushpuppi ma se fi ewon ogun odun gbara.

About AbubakarMuhd

x

Check Also

seun kuti

Orí kó Seun Kuti yọ kúrò lọ́wọ́ ikú ní yàrá ìgbàlejò US

Mary Fágbohùn Olórin Afrobeat Seun Kuti ti fi ìrírí ibanuje ọkàn rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà han nígbà tí ọta ibọn kan gúnlẹ̀ lójú fèrèsé yàrá igbalejo rẹ̀. O salaye ibapade to ba ni lẹru naa lori oju-iwe Instagram rẹ, o fi fidio ferese ti ọta ibọn naa bajẹ ati iho re han. Seun, ẹni ti o ṣalaye iyalẹnu, beere iwoye ti aabo ni Amẹrika. Ninu fonran naa, Seun Kuti sọ pe oun wa ninu yara igbalejo, ti oun n sinmi, ...