Home / Author Archives: ayangalu (page 20)

Author Archives: ayangalu

O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ àgùnbánirọ̀. (NYSC)

O lè wọ sòkòtò tó tóbi, ṣùgbọ́n kò sí ààyè fún yẹ̀rì,láti sìnrúùlú …Àjọ àgùnbánirọ̀. (NYSC) Fẹ́mi Akínṣọlá Ọ̀gá àgbà fún àjọ àgùnbánirọ̀ lórilẹ̀-èdè Nàìjíríà, Brig. Shuaibu Ibrahim ti sàlàyé fún akọ̀ròyìn pé ààyè wà fún àgùnbánirọ̀ tó bá fẹ́ ...

Read More »

Ẹgbẹ́ Àwọn Àgbààgbà Oòduà Ní Osinbajo Kò Gbọdọ̀ Kọ̀wé Fipò Ẹ̀ Sílẹ̀

Ẹgbẹ́ àwọn àgbààgbà Yorùbá ní Osinbajo kò gbọdọ̀ kọ̀wé fipò ẹ̀ sílẹ̀ Ẹgbẹ́ àwọn àgbààgbà Oòduà (Yorùbá) ní Osinbajo kò gbọdọ̀ kọ̀wé fipò ẹ̀ sílẹ̀ Fẹ́mi Akínṣọlá Èyí ò tófò, kò tófò,fìlà aráabí kù rébété, Kemi Adeoṣun lọ , orí ...

Read More »

Ìjọ Kátólíkì Bẹ̀rẹ̀ Ìwáàdì Lẹ̀yìn Tí Àwọn Sisitá Méjì Lóyún Ójijì

Ìjọ Kátólíkì bẹ̀rẹ̀ ìwáàdì lẹ̀yìn tí àwọn sisitá méjì lóyún ójijì Ìjọ Kátólíkì bẹ̀rẹ̀ ìwáàdì lẹ̀yìn tí àwọn sisitá méjì lóyún ójijì Fẹ́mi Akínṣọlá Eemọ̀ lukutu pẹ́bẹ́,kò síbi tí ìṣe ò sí. Ayé dojú kejì, wọ́n ń bámí ẹran níhòòdí ...

Read More »

Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ

Seyi Makinde ṣe àbẹ̀wò sí ibùdó ìtọ́jú èèyàn 200 tí ọlọ́pàá tú sílẹ̀ ní ilé Ọlọ́rẹ Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́Seyi Makinde ti se àbẹ̀wò sí ilé Ọlọrẹ tó wà ní àdúgbò Ọ̀jọ́ nílùú Ibadan .Bẹ́ẹ̀ bá gbàgbé, ilé yìí ...

Read More »

N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele

N kò leè fi ìdúnú mi pamọ́ lọ́jọ́ ìkómọ àwọn ìbẹta….Yinka Ayefele Fẹ́mi Akínṣọlá Ẹ̀dá ò láròpin láyé, ṣé bí ó se wu Olúwa Ọba níí sọlá, fẹ́ni Ó wù ú,bẹ́ẹ̀ gẹ́lẹ́ ni ọ̀rọ̀ níbi tí t’ọba, tìjòyè, ọ̀tọ̀kùlú ìlú ...

Read More »

Èmi ò kì ń s̩e “His Excellency” – Sanwo-olu

Ogbeni Babajide Sanwo-olu ni mi. Mi o ki n n se “His excellency”.Gomina ipinle Eko lo n salaye yii fun awon oniroyin lonii ojo kefa osu kokanla odun yii.Gomina ni igberaga wa ninu oruko ” His Excellency “. E saa ...

Read More »

A Dúró Lójú Òpó Ìdájọ́ Ilé Ẹjọ́ Àkọ́kọ́ Lórí Ẹjọ́ Ajimobi – Adájọ́

A dúró lójú òpó ìdájọ́ ilé Ẹjọ́ àkọ́kọ́ lórí ẹjọ́ Ajimobi – Adájọ́ Fẹ́mi Akínṣọlá Gómìnà àná ní Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Abiola Ajimọbi ti fìdí rẹmi nínú ìpẹ̀jọ́ rẹ̀ láti tako ìbò tí ó gbé ojúgbà rẹ̀ Kọla Balogun wọlé gẹ́gẹ́ ...

Read More »

Àṣírí Pásìtọ̀ Tó Ń Fí Sọ́ọ̀si Ṣe Ọ̀gbà Wèrè Tú

Àṣírí pásìtọ̀ tó ń fí sọ́ọ̀si ṣe ọ̀gbà wèrè tú Fẹ́mi Akínṣọlá Ṣé biribiri òkuǹkùn ọ̀rọ̀ lójú ọmọ aádámọ̀ ,ìmọ̀lẹ̀ gbòò ni lójú Adẹ́dàá. Ní báyìí, Olùsọ́ àgùtàn Joseph Ojo, ní ọwọ ṣìnkún ọlọpàá ti mú fún lílo ilé ìjọsìn ...

Read More »

Ayédèrú ni ‘plate number Chief Whip’ Kano – FRSC

Iroyin asise nomba moto asofin ilu Kano, Ogbeni Ayuba Durum ran kaakiri bi ina inu oye, paapaa julo lori ero ayelujara. Eyi wa ya gbogbo aye lenu pe se bee ni awon ajo FRSC tii se adari eto irinna ati ...

Read More »

Lai Mohammed fa o̩mo̩ Naijiria létí lórí ìròyìn òfegè

Lai Mohammed fa ọmọ Nàìjíríà létí lórí ìròyìn òfegè Fẹ́mi Akínṣọlá Mínísítà ètò ìbáraẹnisọ̀rọ̀ àti Ìròyìn lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, Lai Mohammed ti ní ìjọba yóò bẹ̀rẹ̀ ṣí í ṣe àmójútó àtagbà ojú òpó ayélujára báyìí.Ìgbésẹ̀ yìí ni láti ṣe àfọ̀mọ́ ojú ...

Read More »