Ipokipo ti eda ba wa laye, e pe ko maa dupe. Ibikibi ti ori ba da ni si ka fi ope fun Oluwa oba nitori awon kan ko tile ni ida kan ninu ogorun anfaani ti a ni. Ebi n ...
Read More »Won Fi Leta Pe Pasuma Pe Ko Wa Korin Ni Soosi Baba G.O Adegboye
Abi foto Buroda Alabi Pasuma ko ni mo n wo yii ni? Ko ma si eni ti Olorun ko le fi owo to lokan sa o. Burudo Pasuma, Orobokibo Creator, Oga Nla 1, Ijaya of Fuji, Oluwa yoo ma so ...
Read More »Sayewo Omo Ita, Jaguda Ti Buhari Fi Se Oludamora Nipa Oro To N Lo Nile Igbimo Asofin
Honorebu Suleiman A. Kawu ni yii, okan ninu awon omo ile igbimo asofin ti n fo iganna nigba rogbodiyan to waye nile igbimo asofin ni akoko ti Goodluck Jonathan wa lori oye gege bi Aare ile Nigeria olominira. Maanu yii ...
Read More »Oko Toyin Aimakhu, Adeniyi Johnson Ti Dale Ife
Laipe yii ni omobirin naa yo oruko oko re kuro ninu oruko re. Bakan naa ni awon eniyan tun kiyesi wi pe awon foto oko re to wa lori ikanni instagram re lo ti fe e gbonyo tan. Adeniyi Johnson ...
Read More »“Kini Idi Ti Fasola Fi Wu Ewu Funfun Lori Ko To Kuro Nijoba?” Ninu Iwe Iroyin Owuro Ni Idahun Naa Wa
Akole gbagada to jade lati inu iwe Iroyin Owuro ti ose yii lo n so nipa ohun to faa ti Fasola fi wu ewu lori ko to pari ijoba re nigba ti awon akegbe re bi Mimiko ati Ajimobi n ...
Read More »Awon Omo Ologun Ile Nigeria Fi Emi Awon Omo Boko Haram Ti Won Woso Ologun Sorun Sofo Bi Omi Efo
Asiri awon omo Boko Haram kan ti won wo aso ologun sorun sise buburu owo won ti tu ni apa ila oorun-arewa ile Nigeria. Awon omo Ologun Nigeria yosi won ni ibuba won ti won go si, won si se ...
Read More »Adajo Ti Dajo Iku Fun Omobirin To Gbe Ogun-Oloro Pamo Si Oju-Ara Re Ni Ilu Thailand
Ile ejo ti dajo iku fun Chonmanee Laphathanawat, eni ogbon (30) odun ni ilu Thailand pelu esun gbigbe ogun oloro cocaine ni orileede Thailand. Omobirin yii ni won mu pelu bo se sin ogun-oloro ti won ti ro sinu kapusu ...
Read More »Aja Je Omo Tuntun Niluu Asaba !
Abiyamo Padanu Omo Re Kan Soso Sinu Agbara Eje Isele kan to sele lojo Eti to koja yii ni Asaba to wa ni Ipinle Delta je eyi to ba ni lokan je jina. Arabirin kan, eni odun metadinlogoji (37), Maureen ...
Read More »Awon foto: Ayeye Igbeyawo Omo Gomina Abiola Ajimobi Le Ku!
Oni ojo kokanlelogun, osu kejo (Aug 21), odun 2015 ni Gomina Abiola Ajimobi n se igbeyawo fun omo re obirin, Ajibola pelu oko omo re, Ayokunle Olayiwola. Orisirisi awon eniyan nlanla ati awon gomina lati apa iwo-oorun guusu Naijeria ni ...
Read More »Eledumare ki odun yi to pari kole temi fun mi….iwo nko ?
Ase !
Read More »