Odù ifá tí ó sòkalè ni *ìretè-ìká* ifá pé ire aya (couples blessing) ifá ní a ó se òpòlopò Odún láyé. Ifá ní kí á rúbo lópòlopò wípé Odún yìí yóò sàn wá fún ajé, aya, Omo, ogbó ató àti ...
Read More »Ooni ti ile-ife ní ìdí òpe àgùnká .
Ayeye Odún ifá àgbáyé eléyìí tí ó wáyé ní òkè-ìtase ní ilú ilé-ifè. Ooni rèé ní ìdí òpe àgùnká ní ibi tí mùtúmùwà ti ń se àdúrà sí ìsèdá won, kódà oba náà kò jáfara.
Read More »Ìwúre Òṣù Tuntun
Bí ÒṢÙ bá yọ loke terutọmọ niiri, omi ajipon kiiru, ninu ÒṢÙ kẹfa yi aye gbogbo wa yio toro minimini, bi Ọgẹdẹ ba pọn ará aa dẹẹ, ara oni ni emi àti Ìwọ oluka àtèjìṣẹ mi yi, àtijẹ atimu koni ...
Read More »Oríkì Fún Ọba
Kábíyèsí Ọba Olúwayé, Ọ̀dúndún aṣọ̀’de d’ẹ̀rọ̀, Ọba adé-kí-ilé-r’ójú Ọba ade-kí-ọ̀nà-rọrùn, Arówólò bí òyìnbó, Ó fi’lé wu ni, O f’ọ̀nà wu ni. Ògbìgbà tí n gba ará àdúgbò Ọba at’áyé-rọ bí agogo.
Read More »Ifá náà ki bayi wípé: Eye òkun, Eye òsà
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku amojuba osù tuntun òkudù yi, osù tuntun náà yio sanwa sowo, somo ati si aiku baale orò o, mosi tun fi asiko yi ki gbogbo awa onisese lagbaye wípé aku odun bara mi ...
Read More »Yoruba Du’n Gbo Lenu Saraki
A kú òsè jàkúta.
Sango oooo Olukoso ayanran ina Ina loju, ina lenu Sangiri, lagiri Olagiripapa figba edun bo Eefin ina la n da laye Ina nbe lodo oko mi lorun Abaabe ooooooooo Abaabe laba Se fun SANGO Emi Se SANGO labaabe Agbenajo, Agbenayan ...
Read More »Àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó tokotayà yí ti won pàdé nígbà tí won ń sin orílè èdè won lówó ní odún mérin séyìn.
Arábìnrin Nìjíríà kan tí a mò sí Rosemary nípa eni tí yó sèsè di oko rè Láìpé odún màrún-ùn séyìn, nígbà tí won ń sin orílè èdè won lówó ní Kaduna ti pín àwòrán kí ó tó di ojó ìgbeyàwó ...
Read More »Fúlàní darandaran pa àwon èèyàn ní ojú ònà Makarda ní òpópónà Makarda.
Óní òun so gbangba gbàngbà ni Láì bèrù enikéni :báyìí ni Adamu Donald Dekwagh, wípé enikéni kò gbodò sùn nígbà tí igbákejì Ààre orílè èdè lo kí won ní Benue ní ànà yí tí àwon wòólì méjì àti darandaran pa. ...
Read More »Òdókùnrin kan ní àwon olópàá yin ìbon pa nígbà tí won fé parí ìjà ní Ajegunle.
Òdókùnrin kan tí a gbó wípé ó jé omo ogún odún ni a gbó wípé won fi èsùn kàn àwon olópàá Látàrí ìbon tí won yìn pa Òdókùnrin yí, nígbà tí won ń parí ìjà lówó láàrin àwon ìkò ológun ...
Read More »