Home / Iroyin Pajawiri (page 51)

Iroyin Pajawiri

A kú àmójúbà Osù Eréna (March) tuntun.

Osù ìdèra, ìtèsíwájú, ìse rere ni yóò jé fún gbogbo wa. Nínú Osù tuntun yìí, àìsàn kò níí jé ìpín enìkóòkan wa. Eni yòówù tí àìlera bá n dà láàmú, Olódùmarè yóò so ó dèrò. A kò níí rí ìjà ...

Read More »

Àwon ológun orílè èdè Nàíjíríà ya àwòrán pèlú ejò rògbòdò léyìn tí won pa á tán .

   Àwon ikò ológun ni inú won n dùn tí won sì n yò léyìn tí won pa ejò nla rògbòdò kan níbi tí won tèdó sí . Àwon Akoni yí ya àwòrán pèlú eranko afayàfà yí nígbà tí inú ...

Read More »

Alágbárí òdómokùnrin kan tí a mò sí yahoo boy lo omo ègbón rè okùnrin tí kò ju omo odún méje lo láti fi se ògùn owó ní ìlú èkó .

    Òdómokùnrin kan ni owó àwon agbófinró tè nígbà tí ó n lo omokùnrin ègbón rè láti fi se ògùn owó ní ìlú èkó. Gégé bí a se gbó, orúko òdómokùnrin tí a fi èsùn kan ni Tunde Owolabi ...

Read More »

E wo nkan tí ilé-èkó gíga ifáfitì ti ìlú Èkó tí a mò sí UNILAG se! Sé eléyìí kò ní jé kí àwon òdómobìnrin wa n’íìfé ohun afefe yèyè si báyìí.

   Nígbà míràn kò ye kí á bá àwon òdómobìnrin wa tí won n’íìfé ohun ayé wí jù, nígbà tí ó jé wípé àwon àwùjo wa kò kúkú mú orí eni tí n se isé takuntakun wú. Ká sisé kára ...

Read More »

Ifá náà ki bayi wípé: Adaku Adaoku

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi, aku ise ana o, a si tun ku imura toni, gegebi a se mo wípé oni je ojó isegun, ogun buburu yio se ninu igbesi ayé wa loni o Àse. E jeki a fi ...

Read More »

Oko àti ìyàwó se ayeye ojó ìbí won nígbà tí won pé ogóòrún (100) àti márùndínlógóòrún papò.

   Bàbá bàbá kan tí ó jé bàbá orílè èdè Nàìjíríà àti ìyá ìyá ni won se ayeye ojó ìbí fún nígbà tí won pé ogóòrún àti márùndínlógóòrún. Gégé bí olùsòrò kan lórí èro ayélujára se so àti olùsòrò gbogbogbò ...

Read More »

Àwon tí won ti yo kúrò àti àwon tí won lé ní BBNaija ti se àyéwò sí ilé-ìfowópamó tí a mò sí Heritage bank.

    Àwon Alábagbélé àti olùgbépò télè ti big brother Naija, àwon tí a mò sí Vandora, Princess, Dee one , Bitto àti àwon tí won lé kúrò Khloe àti k Brule se àbèwò sí ìkan lára àwon ilé-isé tí ...

Read More »

Òkan l’ára àwon anamoyayà (civil defence officer) ni àwon fúlàní darandaran pa ní ìpínlè Benue tí won sì sin ín pélú omijé.

Anamoyayà (civil defence officer) ni àwon Fulani darandaran pa ní ìjoba ìbílè Guma ní ìpìnlè Benue ni won ti sín pèlú òpòlopò omijé. Àwon emèwà rè ti sin ín tomijé tomijé.

Read More »

Arákùnrin kan tí ó jé ígbó àti arábìnrin òyìnbó yí se ayeye ìgbéyàwó ìbílè won.

Arákúnrin tí ó jé ígbò yí ti se ayeye ìgbéyàwó ìbílè alárinrin, tí ó sì ti fé ìyàwó rè òyìnbó n’ísu l’ókà. Gégé bí ìgbéyàwó náà se wáyé ní ojó ketàdínlógún osù kejì odún yí (17/2/2018) , a rí àwòrán ...

Read More »

E wo Nkan ti Obesere so Nipa Pasuma Ati Awon Osere Oni Fuji miran !

Read More »