Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku ise ana o, mogbaladura laaro yi wipe eledumare koni jeki enikookan wa jaye inira loni ase. Laaro yi mo nfe ki a mo iwulo ewe to wa ninu aworan yi ninu odu ifa ...
Read More »“Kíní ó ye’kú nùn l’Órí Awo?
Èjì Òyè Ifá ní ó ye’kú nùn l’Órí Awo What will avert death away from Awo? Èjì Òyè Ifa will avert death away from Awo.” ~Owó
Read More »Danrogbo ati Opapa
Danrogbo, Opapa, Owarowaro, Danrogbo ni won n pe iku, Opapa ni won n pe arun, Owarowaro ni won n pe ekun, Igbo loni ki ori wa gbo kaka di ale, Bi igbin ba dagba,a darugbo kegekege, Ki iku ma ji ...
Read More »Eku Apere Ninu Ile Nla
Moki gbogbo apapo ojogbon awo mimo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi ooo Wipe :- (.KINNIHUN ORUNMILA OO.) (Ilosiwaju ishese lo jemi lo gun ooo) EJOWO OO E NPE MI SI AKIYESI Oruko mi ni iyin oluwa moje enikan ...
Read More »Aki Ijo Kinnihun Orunmila
(Atorieni Tikosun wonSe) TI ILU IBADAN LAPAPO OOO Aki gbogbo ojogbon awo mimo lapapo lagbaiye ninu ile nla I.K.O. nla wayi oo Wipe :- (KINNIHUN ORUNMILA O) (ilosiwaju ishese lo jemi lo gun o) Aki gbogbo apapo ojogbon awo mimo ...
Read More »Iwure Ojo Aje 3/10/2016
Ekaro oo se dara dara laji lowuro eni o gege bi emi na se ji oo toba ribee ejekia dupe lowo olodumare kiafi okan kan dupe lowo eleda wa ejekia bo si iwaju oke ipori wa pelu obi tabi eyi ...
Read More »Olojo Ibi Toni
Mo layo lati so fun yin wipe oni ni ojo ibi Princess Oluwakemi Morenikeji Idowu ti won je okan pataki ninu ebi Omo Yoruba Atata. Olojo ibi oni a ki yin e ku ayo oni, e o se pupo re ...
Read More »Odu Ifa Iwure Toni Ki Bayi Wipe..
Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Eku ojo meta o, Ogun lakaye yio bawa segun awon ota wa yio si lana ire gbogbo funwa loni ase. Odu ifa iwure toni ki bayi wipe: Irete Osa kubu irete Osa kebe, irete ...
Read More »Ayeye Ojoibi Toni: Babami Oloye Olatbosun Oladapo
Ododun larorogbo Ododun lari awusa Ododun lati mo obi lori ate Ododun ni sapo nruwe Ododun ni peregun yio Ododun leo ma bee ninu ola ati Alaafia Alekun ogbon Alekun Oye Alekun IMO Alekun emi gigun Alekun Alaafia Oju asa ...
Read More »Ori mi segbe leyin mi ooo..
Ori eni lawure eni ni, Ori mi segbe leyin mi ooo. Ori a gbe wa o.Ase oo
Read More »