Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Idile Alayo wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...
Read More »Ounje UNJE Eme Fun T’ooro Yii – 26.05.2016
HUN ! B’o ti wu ki a pe laye to … A pee lorun ju bee lo… :::: WOO ORE WA ! #Igba o lo bi #Orere.. Bee, #Laye taa wa yii ko lo bi #Opa_ibon ::::::: DAKUN ORE WA ...
Read More »Odo Iwoyi – 2
Mo ki gbogbo Omo Yoruba Atata pata nile-loko ati leyin odi wipe a ku dede asiko yi, mo si ki awa ololufe eto Odo Iwoyi wipe e ku abo sori eto wa, eto yin, eto Odo Iwoyi ti ose yi. ...
Read More »Eeto Owe L’esin Oro – 3
A ku deede asiko yii o ni aafin ilumoye, moki gbogbo wa kaabo si akotun eeto yin, eeto wa OWE L’ESIN ORO, oro l’esin owe ti oro ba sonu owe ni a o fi waa jade. Ope nla lo si ...
Read More »Ogulutu Oro Toni – 24.05.2016
Wo binu ba nbio masoro, tinu re basi ndun mase ile ri, fi eniyan buburu sile saye re. # wo Mase mura lati gbija arare fija le f’OLOHUN,ohun nikan loba elesan….. Ire oo
Read More »Iwure Owuro Toni – 24.05.2016
E MAA WI TELE MI : ………. *Eledumare tete wa pa mi lerin ayo. *Ajalu buruku ko ni sele si mi. *Edumare ba mi segun alatako. *Emi ko ni subu fun ota yo. *Apari inu mi ko ni ba tode ...
Read More »Lori Eto Tonii: Kini nje Ela ?
* Kin ni nje ELA ? Abi Taani #ELA je gan-an ? * Nje ESIN ati #ASA Yoruba tako ara won bi ? * Bawo ni # Ela_boru , Ela Boye , Ela bo sise se je Ede ikini fun ...
Read More »Oro re e gbe ye wo
hmnmmmmmm ojulu oooo!, E gbo nti omodekunrin olorin yi(adeekunle gold) nfi orin nwi? O nipe okunrin olowo-agbaye(aliko-dangote) yi ko ni ori-meji o ni oun nan fe lowo bi dangote oun fe gun moto-boginni(range-rover) oun fi kadara we karaole oun fi ...
Read More »Iyawo elese-osun ati oko-iyawo-elese-osun
Base fe kori benan lori emi lao ni yo si, leyin iwa ewa lotun ku pelu ase Edumare iyawo elese-osun ati oko-iyawo-elese-osun ori koni tako yin leyin igeyawo yi ati titilailai, ogede ki gbodo koya agan, iyawo yo finu soyun ...
Read More »Eeto Owe L’esin Oro
A ku deede asiko yii o gbogbo olugbe aafin ilumoye, eeto yin eeto wa owe l’esin oro ni o tun wole de weere yi ooo, e wa nkan fidile ki a dijo gbadun eeto ti toni. Siwaju ki eeto o ...
Read More »