Eyin ojogbon eniyan, kini itumo awon oro won yii ?
Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile. Oni baba re n ko? Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja” Iya ...
Read More »Enikan lo lo ki ore re,ko si ba ore re nile, sugbon o ba okan ninu awon omo ore re nile. Oni baba re n ko? Omo naa ni:”Baba mi lo so okun (rope) aye ti o fe ja” Iya ...
Read More »Eku Dede Asiko Yi Ni Gbogbo Ibi Ta A’Ba Wa o
Oruko mi ni TINUKE mofe ki eyin omo ilu yi gbami ni yanju lori oro yi ni ooooo Lati bi osu marun se yin ni ago ibani soro kan man pe mi Ti eni yen ba pe mi EPE nla ...
Read More »Ki ni oruko kini yi o ?
Omo Ooduarere ki ni oruko kini yii ?
Read More »E Jowo Ninu Iyabo Ojo Ati Mercy Aigbe Tale Feran Ju?
Ohun to pada sele si maanu to lo gbadun ara re nile asewo buru jai
Maanu yii lo lo gbadun ara re nile asewo kan niluu Benin. Aisanwo leyin igbadun lo di ohun ti won da igbati jo fun un.
Read More »Senato ipinle Ekiti pin iresi fun awon eniyan bi Fayos
Awon eniyan ti won gbe ni agbegbe ekun Guusu Ekiti gbajo tilu tifon nigba ti arabirin Biodun Olujimi ti n soju won nile igbimo asofin agba Abuja si obitibiti ounje wolu l’Ojobo ose to koja yii. Apo iresi, ororo ati ...
Read More »“Awon irinse ti a n lo ti darugbo”- Oga panapana ilu Eko
Oga agba ileese panapana ti ijoba apapo, Federal Fire Service, eka ti ipinle Eko, Ogbeni Aderemi Olusola Theophilus ti sapejuwe ikiyesara gege bi ogun-ajisa lati dena ijamba ina abaadi. Ninu oro re, eleyii to so lori telifisan ipinle Eko, o ...
Read More »